Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ tí Olúwa ti sọ nípa rẹ̀, ẹ̀yin ènìyàn Israẹli nípa àwọn ìdílé tí mo mú jáde láti Ejibiti:
KO
Copywork
Yoruba OYCB 아모스 3장
성경필사는 빠르게 끝내는 입력 훈련이 아니라, 한 절씩 말씀의 문장과 흐름을 다시 붙드는 시간입니다. 입력 내용은 이 브라우저에 임시 저장되며, 로그인하면 계정에도 저장됩니다.
소제목 단위로 진행 · 아모스
“Ìwọ nìkan ni ẹni tí mo yàn
Ẹni méjì ha à le rìn pọ̀
Ǹjẹ́ Kìnnìún yóò ha bú ramúramù nínú igbó,
Ǹjẹ́ ẹyẹ ṣubú sínú okùn ọdẹ lórí ilẹ̀
Nígbà tí ìpè bá dún ní ìlú,
Nítòótọ́ Olúwa Olódùmarè kò ṣe ohun kan
Kìnnìún ti bú ramúramù
Ẹ kéde ní ààfin Aṣdodu
“Wọn kò mọ bí wọ́n ṣe ń ṣe rere,” ni Olúwa wí,
Nítorí náà, báyìí ni Olúwa Olódùmarè wí:
Èyí ni ohun tí Olúwa wí:
“Gbọ́ èyí kí o sì jẹ́rìí nípa ilé Jakọbu,” ni Olúwa wí, Olúwa Ọlọ́run àwọn ọmọ-ogun.
“Ní ọjọ́ tí mo fìyà jẹ Israẹli lórí ẹ̀ṣẹ̀ wọn,
Èmi yóò wó ilé òtútù