scripture.how 성경필사
KO

Copywork

Yoruba OYCB 요엘 2장

성경필사는 빠르게 끝내는 입력 훈련이 아니라, 한 절씩 말씀의 문장과 흐름을 다시 붙드는 시간입니다. 입력 내용은 이 브라우저에 임시 저장되며, 로그인하면 계정에도 저장됩니다.

KO 한국어
ZH 중국어
JA 일본어
HI 힌디어
BN 벵골어
TA 타밀어
TE 텔루구어
ML 말라얄람어
FA 페르시아어
MY 버마어
NE 네팔어
MR 마라티어
KN 칸나다어
HA 하우사어
YO 요루바어
SW 스와힐리어
IG 이그보어
ID 인도네시아어
TSI
PT 포르투갈어
VI 베트남어
AR 아랍어
AVD
RU 러시아어
UK 우크라이나어
RO 루마니아어
BTF
IT 이탈리아어
FI 핀란드어
TO 통가어
HR 크로아티아어
SR 세르비아어
TR 튀르키예어
HU 헝가리어
PL 폴란드어
SK 슬로바키아어
LA 라틴어
NL 네덜란드어
CS 체코어
FR 프랑스어
ES 스페인어
DE 독일어
ETC 기타 언어
2:1
대기

Ẹ fun ìpè ní Sioni,

2:2
대기

Ọjọ́ òkùnkùn àti ìrọ́kẹ̀kẹ̀,

2:3
대기

Iná ń jó níwájú wọ́n;

2:4
대기

Ìrí wọn dàbí ìrí àwọn ẹṣin;

2:5
대기

Bí ariwo kẹ̀kẹ́ ogun ni

2:6
대기

Ní ojú wọn, àwọn ènìyàn yóò jẹ ìrora púpọ̀:

2:7
대기

Wọn yóò sáré bi àwọn alágbára;

2:8
대기

Bẹ́ẹ̀ ni ẹnìkan kì yóò kọlu ẹnìkejì rẹ̀;

2:9
대기

Wọn yóò sáré síwá sẹ́yìn ní ìlú;

2:10
대기

Ayé yóò mì níwájú wọn;

2:11
대기

Olúwa yóò sì bú ramúramù

2:12
대기

“Ǹjẹ́ nítorí náà nísinsin yìí,” ni Olúwa wí,

2:13
대기

Ẹ sì fa ọkàn yín ya,

2:14
대기

Ta ni ó mọ̀ bí òun yóò yípadà, kí o sì ronúpìwàdà,

2:15
대기

Ẹ fún ìpè ní Sioni,

2:16
대기

Ẹ kó àwọn ènìyàn jọ,

2:17
대기

Jẹ́ kí àwọn àlùfáà, àwọn ìránṣẹ́ Olúwa,

2:18
대기

Nígbà náà ní Olúwa yóò jowú fún ilẹ̀ rẹ̀,

2:19
대기

Nítòótọ́, Olúwa yóò dá wọn lóhùn, yóò sì wí fun àwọn ènìyàn rẹ̀ pé:

2:20
대기

“Ṣùgbọ́n èmi yóò lé ogun àríwá jìnnà réré kúrò lọ́dọ̀ yín,

2:21
대기

Má bẹ̀rù, ìwọ ilẹ̀;

2:22
대기

Ẹ má bẹ̀rù, ẹranko igbó,

2:23
대기

Ẹ jẹ́ kí inú yín dùn, ẹ̀yin ọmọ Sioni,

2:24
대기

Àwọn ilẹ̀ ìpakà yóò kún fún ọkà;

2:25
대기

“Èmi yóò sì mú ọdún wọ̀nyí ti eṣú jẹ run padà fún un yín.

2:26
대기

Ẹ̀yin yóò ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ láti jẹ, títí ẹ̀yin yóò fi yó

2:27
대기

Ẹ̀yin yóò sì mọ̀ pé, èmi wà láàrín Israẹli,

2:28
대기

“Yóò sì ṣe níkẹyìn ọjọ́,

2:29
대기

Àti pẹ̀lú sí ara àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ ọkùnrin,

2:30
대기

Èmi yóò sì fi iṣẹ́ ìyanu hàn ní ọrun

2:31
대기

A á sọ oòrùn di òkùnkùn,

2:32
대기

Yóò sí ṣe, ẹnikẹ́ni tí ó ba ké pè