Báwo ni wúrà ṣe sọ ògo dídán rẹ̀ nù,
KO
Copywork
Yoruba OYCB 예레미야애가 4장
성경필사는 빠르게 끝내는 입력 훈련이 아니라, 한 절씩 말씀의 문장과 흐름을 다시 붙드는 시간입니다. 입력 내용은 이 브라우저에 임시 저장되며, 로그인하면 계정에도 저장됩니다.
소제목 단위로 진행 · 예레미야애가
Báwo ni àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin Sioni tí ó ṣe iyebíye,
Àwọn ajáko pèsè ọmú wọn
Nítorí òǹgbẹ, ahọ́n àwọn ọmọ ọwọ́
Àwọn tí ó ń jẹ ohun dáradára
Ìjìyà àwọn ènìyàn mi
Ọmọ ọba ọkùnrin wọn mọ́ ju òjò-dídì,
Ṣùgbọ́n nísinsin yìí wọ́n dúdú ju èédú;
Àwọn tí ó kù nípasẹ̀ idà sàn
Pẹ̀lú ọwọ́ àwọn obìnrin aláàánú
Olúwa ti fi ihò kíkún fún ìbínú rẹ̀;
Àwọn ọba ayé kò gbàgbọ́,
Èyí ṣẹlẹ̀ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn wòlíì
Nísinsin yìí wọ́n ń rìn kiri ní òpópó
“Lọ kúrò! Ẹ̀yin di aláìmọ́!” ni àwọn ènìyàn ń kígbe sí wọn.
Olúwa ti tú wọn ká fúnra rẹ̀;
Síwájú sí i, ojú wa kùnà
Wọ́n ń ṣọ́ wa kiri,
Àwọn tí ń lé wa yára
Ẹni àmì òróró Olúwa, èémí ìyè wa,
Ẹ yọ̀ kí inú yín sì dùn, ẹ̀yin ọmọbìnrin Edomu,
Ìwọ ọmọbìnrin Sioni, ìjìyà rẹ yóò dópin;