Ègbé ni fún ìlú ẹ̀jẹ̀ nì,
KO
Copywork
Yoruba OYCB 나훔 3장
성경필사는 빠르게 끝내는 입력 훈련이 아니라, 한 절씩 말씀의 문장과 흐름을 다시 붙드는 시간입니다. 입력 내용은 이 브라우저에 임시 저장되며, 로그인하면 계정에도 저장됩니다.
소제목 단위로 진행 · 나훔
Ariwo pàṣán àti ariwo
Ológun orí ẹṣin ń fi ìgbónára
Nítorí ọ̀pọ̀lọpọ̀ panṣágà
“Èmi dojúkọ ọ́,” ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí.
Èmi yóò da ẹ̀gbin tí ó ni ìríra sí ọ ní ara,
Gbogbo àwọn tí ó ba sì wò ọ́ yóò sì káàánú fún ọ, wọn yóò sì wí pé,
Ǹjẹ́ ìwọ ha sàn ju Tebesi lọ,
Etiopia àti Ejibiti ni agbára rẹ, kò sí ní òpin;
Síbẹ̀síbẹ̀ a kó o ní ìgbèkùn
Ìwọ pẹ̀lú yóò sì mu àmupara;
Gbogbo ilé ìṣọ́ agbára rẹ yóò dàbí igi ọ̀pọ̀tọ́
Kíyèsi gbogbo àwọn jagunjagun!
Pọn omi nítorí ìhámọ́,
Níbẹ̀ ni iná yóò ti jó ọ́ run;
Ìwọ ti sọ àwọn oníṣòwò rẹ di púpọ̀
Àwọn aládé rẹ̀ dàbí eṣú,
Ìwọ ọba Asiria,
Kò sì sí ohun tí ó lè wo ọgbẹ́ ẹ̀ rẹ sàn;