Ẹ kó ara yín jọ pọ̀, àní ẹ kó ra yín jọ pọ̀
KO
Copywork
Yoruba OYCB 스바냐 2장
성경필사는 빠르게 끝내는 입력 훈련이 아니라, 한 절씩 말씀의 문장과 흐름을 다시 붙드는 시간입니다. 입력 내용은 이 브라우저에 임시 저장되며, 로그인하면 계정에도 저장됩니다.
소제목 단위로 진행 · 스바냐
kí a tó pa àṣẹ náà, kí ọjọ́ náà tó kọjá bí ìyàngbò ọkà,
Ẹ wá Olúwa, gbogbo ẹ̀yin onírẹ̀lẹ̀ ilẹ̀ náà,
Nítorí pé, a ó kọ Gasa sílẹ̀,
Ègbé ni fún ẹ̀yin tí ń gbé etí Òkun,
Ilẹ̀ náà ní etí Òkun, ni ibùgbé àwọn ará Kereti,
Agbègbè náà yóò sì jẹ́ ti ìyókù àwọn ilé Juda,
“Èmi ti gbọ́ ẹ̀gàn Moabu,
Nítorí náà, bí Èmi tí wà,”
Èyí ni ohun tí wọn yóò gbà padà nítorí ìgbéraga wọn,
Olúwa yóò jẹ́ ìbẹ̀rù fún wọn;
“Ẹ̀yin Etiopia pẹ̀lú,
Òun yóò sì na ọwọ́ rẹ̀ sí apá àríwá,
Agbo ẹran yóò sì dùbúlẹ̀ ni àárín rẹ̀,
Èyí ni ìlú aláyọ̀ tí ó ń gbé láìléwu.