scripture.how Bible Copywork
EN

Copywork

Yoruba OYCB Nahum 1장

Copywork is not a speed-typing drill but time to re-hold the words and flow of Scripture, one verse at a time. Your input is saved temporarily in this browser, and to your account when you are signed in.

KO Korean
ZH Chinese
JA Japanese
HI Hindi
BN Bengali
TA Tamil
TE Telugu
ML Malayalam
FA Persian
MY Burmese
NE Nepali
MR Marathi
KN Kannada
HA Hausa
YO Yoruba
SW Swahili
IG Igbo
ID Indonesian
TSI
PT Portuguese
VI Vietnamese
AR Arabic
AVD
RU Russian
UK Ukrainian
RO Romanian
BTF
IT Italian
FI Finnish
TO Tongan
HR Croatian
SR Serbian
TR Turkish
HU Hungarian
PL Polish
SK Slovak
LA Latin
NL Dutch
CS Czech
FR French
ES Spanish
DE German
ETC Other languages
1:1
Waiting

Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ nípa Ninefe. Ìwé ìran Nahumu ará Elkoṣi.

1:2
Waiting

Ọlọ́run ń jẹ owú, ó sì ń gbẹ̀san,

1:3
Waiting

Olúwa lọ́ra láti bínú, ó sì tóbi ní agbára;

1:4
Waiting

Ó bá òkun wí, ó sì mú kí ó gbẹ;

1:5
Waiting

Àwọn òkè ńlá wárìrì níwájú rẹ̀,

1:6
Waiting

Ta ni ó lé dúró níwájú ìbínú rẹ̀?

1:7
Waiting

Rere ni Olúwa,

1:8
Waiting

ṣùgbọ́n pẹ̀lú ìkún omi ńlá

1:9
Waiting

Kí ni ẹ̀yìn ń gbìmọ̀ lòdì sí Olúwa?

1:10
Waiting

Wọn yóò sì lọ́lù papọ̀ bí ẹ̀gún òṣùṣú

1:11
Waiting

Láti ọ̀dọ̀ rẹ, ìwọ Ninefe, ni ẹnìkan ti jáde wá

1:12
Waiting

Báyìí ni Olúwa wí:

1:13
Waiting

Nísinsin yìí ni èmi yóò já àjàgà wọn kúrò ní ọrùn rẹ

1:14
Waiting

Olúwa ti fi àṣẹ kan lélẹ̀ nítorí tìrẹ Ninefe:

1:15
Waiting

Wò ó, lórí àwọn òkè,