Gẹ́gẹ́ bí òkú eṣinṣin tí ń fún òróró ìkunra ní òórùn búburú,
KO
Copywork
Yoruba OYCB 전도서 10장
성경필사는 빠르게 끝내는 입력 훈련이 아니라, 한 절씩 말씀의 문장과 흐름을 다시 붙드는 시간입니다. 입력 내용은 이 브라우저에 임시 저장되며, 로그인하면 계정에도 저장됩니다.
소제목 단위로 진행 · 전도서
Ọkàn ọlọ́gbọ́n a máa ṣí sí ohun tí ó tọ̀nà,
Kódà bí ó ti ṣe ń rìn láàrín ọ̀nà,
Bí ìbínú alákòóso bá dìde lòdì sí ọ,
Ohun ibi kan wà tí mo ti rí lábẹ́ oòrùn,
A gbé aṣiwèrè sí ọ̀pọ̀ ipò tí ó ga jùlọ,
Mo ti rí ẹrú lórí ẹṣin,
Ẹnikẹ́ni tí ó bá gbẹ́ kòtò, ó le è ṣubú sínú rẹ̀;
Ẹnikẹ́ni tí ó bá gbe òkúta le è ní ìpalára láti ipasẹ̀ wọn;
Bí àáké bá kú
Bí ejò bá ṣán ni kí a tó lo oògùn rẹ̀,
Ọ̀rọ̀ tí ó wá láti ẹnu ọlọ́gbọ́n a máa ní oore-ọ̀fẹ́
Ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀ rẹ̀ jẹ́ òmùgọ̀;
Wèrè a sì máa ṣàfikún ọ̀rọ̀.
Iṣẹ́ aṣiwèrè a máa dá a lágara
Ègbé ni fún ọ, ìwọ ilẹ̀ tí ọba ń ṣe ìránṣẹ́ rẹ̀
Ìbùkún ni fún ọ, ìwọ ilẹ̀ èyí tí ọba rẹ̀ jẹ́ ọmọ ọlọ́lá,
Bí ènìyàn bá ń lọ́ra, àjà ilé a máa jì
Ẹ̀rín rínrín ni a ṣe àsè fún,
Ma ṣe bú ọba, kódà nínú èrò rẹ,