Orúkọ rere sàn ju ìpara olóòórùn dídùn lọ,
KO
Copywork
Yoruba OYCB 전도서 7장
성경필사는 빠르게 끝내는 입력 훈련이 아니라, 한 절씩 말씀의 문장과 흐름을 다시 붙드는 시간입니다. 입력 내용은 이 브라우저에 임시 저장되며, 로그인하면 계정에도 저장됩니다.
소제목 단위로 진행 · 전도서
Ó dára láti lọ sí ilé ọ̀fọ̀
Ìbànújẹ́ dára ju ẹ̀rín lọ,
Ọkàn ọlọ́gbọ́n wà ní ilé ọ̀fọ̀,
Ó dára láti gba ìbáwí ọlọ́gbọ́n,
Gẹ́gẹ́ bí ẹ̀gún ti ń dún lábẹ́ ìkòkò
Ìrẹ́jẹ a máa sọ ọlọ́gbọ́n di òmùgọ̀,
Òpin ọ̀rọ̀ dára ju ìbẹ̀rẹ̀ rẹ̀ lọ,
Má ṣe yára bínú ní ọkàn rẹ
Má ṣe sọ wí pé, “Kí ni ìdí tí àtijọ́ fi dára ju èyí?”
Ọgbọ́n, gẹ́gẹ́ bí ogún ìní jẹ́ ohun tí ó dára
Ọgbọ́n jẹ́ ààbò
Wo ohun tí Ọlọ́run ti ṣe:
Nígbà tí àkókò bá dára, jẹ́ kí inú rẹ dùn,
Nínú ayé àìní ìtumọ̀ yìí ni mo ti rí gbogbo èyí
Má ṣe jẹ́ olódodo jùlọ
Ìwọ ma ṣe búburú jùlọ kí ìwọ má sì ṣe aṣiwèrè,
Ó dára láti mú ọ̀kan
Ọgbọ́n máa ń mú kí ọlọ́gbọ́n ènìyàn ní agbára
Kò sí olódodo ènìyàn kan láyé
Má ṣe kíyèsi gbogbo ọ̀rọ̀ tí ènìyàn ń sọ
Tí o sì mọ̀ nínú ọkàn rẹ
Gbogbo èyí ni mo ti dánwò nípa ọgbọ́n, tí mo sì wí pé,
Ohun tí ó wù kí ọgbọ́n le è jẹ́,
Mo wá rò ó nínú ọkàn mi láti mọ̀,
Mo rí ohun tí ó korò ju ikú lọ
Oniwaasu wí pé, “Wò ó, eléyìí ni ohun tí mo ti ṣàwárí:
Nígbà tí mo sì ń wá a kiri
Eléyìí nìkan ni mo tí ì rí: