Rántí Ẹlẹ́dàá rẹ
KO
Copywork
Yoruba OYCB 전도서 12장
성경필사는 빠르게 끝내는 입력 훈련이 아니라, 한 절씩 말씀의 문장과 흐름을 다시 붙드는 시간입니다. 입력 내용은 이 브라우저에 임시 저장되며, 로그인하면 계정에도 저장됩니다.
소제목 단위로 진행 · 전도서
kí oòrùn àti ìmọ́lẹ̀
nígbà tí olùṣọ́ ilé yóò wárìrì
nígbà tí ìlẹ̀kùn sí ìgboro yóò tì
Nígbà tí ènìyàn yóò bẹ̀rù ibi gíga
Rántí rẹ̀ kí okùn fàdákà tó já,
Tí erùpẹ̀ yóò sì padà sí ilẹ̀ ibi tí ó ti wà,
“Asán! Asán!” ni Oniwaasu wí.
Kì í ṣe wí pé Oniwaasu jẹ́ ọlọ́gbọ́n nìkan, ṣùgbọ́n ó tún kọ́ àwọn ènìyàn ní ìmọ̀. Ó rò ó dáradára ó sì ṣe àwárí, ó sì gbé ọ̀pọ̀lọpọ̀ òwe kalẹ̀ lẹ́sẹẹsẹ.
Oniwaasu wádìí láti rí àwọn ọ̀rọ̀ tí ó tọ̀nà, ohun tí ó kọ sì dúró ṣinṣin ó sì jẹ́ òtítọ́.
Ọ̀rọ̀ ọlọ́gbọ́n dàbí ẹ̀gún, àkójọpọ̀ ọ̀rọ̀ wọn sì dàbí ìṣó tí a kàn pọ̀ dáradára, tí olùṣọ́-àgùntàn kan fi fún ni.
Àti síwájú láti inú èyí, ọmọ mi, gba ìmọ̀ràn.
Nísinsin yìí,
Nítorí Ọlọ́run yóò ṣe ìdájọ́ olúkúlùkù iṣẹ́