Kíyèsi i, Olúwa,
Copywork input for chapter 3 verse 1
Your input is saved to this browser automatically.
Àwọn akíkanjú àti jagunjagun,
Copywork input for chapter 3 verse 2
Your input is saved to this browser automatically.
balógun àádọ́ta àti àwọn ènìyàn, onípò gíga;
Copywork input for chapter 3 verse 3
Your input is saved to this browser automatically.
“Èmi ó sọ àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin di aláṣẹ wọn,
Copywork input for chapter 3 verse 4
Your input is saved to this browser automatically.
Àwọn ènìyàn yóò sì máa pọ́n ọmọnìkejì,
Copywork input for chapter 3 verse 5
Your input is saved to this browser automatically.
Ọkùnrin kan yóò di ọ̀kan nínú àwọn
Copywork input for chapter 3 verse 6
Your input is saved to this browser automatically.
Ṣùgbọ́n ní ọjọ́ náà ni yóò figbe bọnu pé,
Copywork input for chapter 3 verse 7
Your input is saved to this browser automatically.
Jerusalẹmu ń ta gbọ̀nọ́ngbọ̀nọ́n
Copywork input for chapter 3 verse 8
Your input is saved to this browser automatically.
Ìwò ojú wọn ń jẹ́rìí lòdì sí wọn,
Copywork input for chapter 3 verse 9
Your input is saved to this browser automatically.
Ẹ sọ fún olódodo pé yóò dára fún wọn,
Copywork input for chapter 3 verse 10
Your input is saved to this browser automatically.
Ègbé ni fún ènìyàn búburú! Ìparun wà lórí i wọn,
Copywork input for chapter 3 verse 11
Your input is saved to this browser automatically.
Àwọn ọ̀dọ́mọdé ni o ń pọ́n àwọn ènìyàn mi lójú
Copywork input for chapter 3 verse 12
Your input is saved to this browser automatically.
Olúwa bọ sí ipò rẹ̀ ní ìtẹ́ ìdájọ́
Copywork input for chapter 3 verse 13
Your input is saved to this browser automatically.
Olúwa dojú ẹjọ́ kọ
Copywork input for chapter 3 verse 14
Your input is saved to this browser automatically.
Kín ni èrò yín láti máa run àwọn ènìyàn mi túútúú
Copywork input for chapter 3 verse 15
Your input is saved to this browser automatically.
Olúwa wí pé,
Copywork input for chapter 3 verse 16
Your input is saved to this browser automatically.
Nítorí náà Olúwa yóò mú egbò wá sórí àwọn obìnrin Sioni,
Copywork input for chapter 3 verse 17
Your input is saved to this browser automatically.
Ní ọjọ́ náà, Olúwa yóò já ọ̀ṣọ́ wọn gbà kúrò ti ọwọ́ àti gèlè àti ẹ̀gbà ọrùn tí ó dàbí òṣùpá
Copywork input for chapter 3 verse 18
Your input is saved to this browser automatically.
gbogbo yẹtí, ẹ̀gbà ọwọ́ àti ìbòjú,
Copywork input for chapter 3 verse 19
Your input is saved to this browser automatically.
gbogbo gèlè, ẹ̀gbà ọrùn, ẹsẹ̀ àti àyà, àwọn ìgò tùràrí àti òògùn,
Copywork input for chapter 3 verse 20
Your input is saved to this browser automatically.
òrùka ọwọ́ àti ti imú,
Copywork input for chapter 3 verse 21
Your input is saved to this browser automatically.
àwọn àtàtà aṣọ, àwọ̀lékè, agbádá àti àpamọ́wọ́,
Copywork input for chapter 3 verse 22
Your input is saved to this browser automatically.
dígí wọn, aṣọ funfun nigínnigín ìbòrí àti ìbòjú.
Copywork input for chapter 3 verse 23
Your input is saved to this browser automatically.
Dípò òórùn dídùn, òórùn búburú ni yóò wá,
Copywork input for chapter 3 verse 24
Your input is saved to this browser automatically.
Àwọn ọkùnrin rẹ yóò ti ipa idà ṣubú,
Copywork input for chapter 3 verse 25
Your input is saved to this browser automatically.
Àwọn bodè Sioni yóò sọkún kíkorò, wọn ó ṣọ̀fọ̀,
Copywork input for chapter 3 verse 26