“Èyí ni ohun tí Olúwa sọ fún ẹni òróró rẹ̀,
KO
Copywork
Yoruba OYCB 이사야 45장
성경필사는 빠르게 끝내는 입력 훈련이 아니라, 한 절씩 말씀의 문장과 흐름을 다시 붙드는 시간입니다. 입력 내용은 이 브라우저에 임시 저장되며, 로그인하면 계정에도 저장됩니다.
소제목 단위로 진행 · 이사야
Èmi yóò lọ síwájú rẹ,
Èmi yóò sì fún ọ ní àwọn ọrọ̀ ibi òkùnkùn,
Nítorí Jakọbu ìránṣẹ́ mi
Èmi ni Olúwa, àti pé kò sí ẹlòmíràn;
tí o fi jẹ́ pé láti ìlà-oòrùn
Mo dá ìmọ́lẹ̀, mo sì dá òkùnkùn,
“Ìwọ ọ̀run lókè rọ òjò òdodo sílẹ̀;
“Ègbé ni fún ènìyàn tí ó ń bá Ẹlẹ́dàá rẹ̀ jà,
Ègbé ni fún ẹni tí ó sọ fún baba rẹ̀ pé,
“Ohun tí Olúwa wí nìyìí,
Èmi ni ẹni tí ó dá ilẹ̀ ayé
Èmi yóò gbé Kirusi sókè nínú òdodo mi.
Ohun tí Olúwa wí nìyìí:
Nítòótọ́ ìwọ jẹ́ Ọlọ́run tí ó fi ara rẹ̀ pamọ́,
Gbogbo àwọn tí ó ń gbẹ́ ère ni ojú yóò tì
Ṣùgbọ́n Israẹli ni a ó gbàlà láti ọwọ́ Olúwa
Nítorí èyí ni ohun tí Olúwa wí,
Èmi kò sọ̀rọ̀ níbi tí ó fi ara sin,
“Ẹ kó ara yín jọ kí ẹ sì wá;
Jẹ́ kí a mọ ohun tí yóò ṣẹlẹ̀, fihàn wá,
“Yípadà sí mi kí a sì gbà ọ́ là,
Nípa èmi tìkára mi ni mo ti búra,
Wọn yóò sọ ní ti èmi, ‘Nínú Olúwa nìkan ni
Ṣùgbọ́n nínú Olúwa gbogbo àwọn ìran Israẹli