“Ẹ wá, gbogbo ẹ̀yin tí òǹgbẹ ń gbẹ,
Èéṣe tí ẹ fi ń ná owó fún èyí tí kì í ṣe àkàrà
Tẹ́tí sílẹ̀ kí o sì wá sọ́dọ̀ mi;
Kíyèsi i, mo ti fi òun ṣe ẹlẹ́rìí fún àwọn ènìyàn,
Lóòtítọ́ ìwọ yóò ké sí àwọn orílẹ̀-èdè tí ìwọ kò mọ̀
Ẹ wá Olúwa nígbà tí ẹ lè rí i;
Jẹ́ kí ìkà kí ó kọ ọ̀nà rẹ̀ sílẹ̀
“Nítorí èrò mi kì í ṣe èrò yín,
“Gẹ́gẹ́ bí ọ̀run ti ga ju ayé lọ,
Gẹ́gẹ́ bí òjò àti yìnyín
bẹ́ẹ̀ ni ọ̀rọ̀ mi tí ó jáde láti ẹnu mi wá;
Ẹ̀yin yóò jáde lọ ní ayọ̀
Dípò igi ẹ̀gún ni igi junifa yóò máa dàgbà,