Ègbé ni fún ọ, ìwọ apanirun,
KO
Copywork
Yoruba OYCB 이사야 33장
성경필사는 빠르게 끝내는 입력 훈련이 아니라, 한 절씩 말씀의 문장과 흐름을 다시 붙드는 시간입니다. 입력 내용은 이 브라우저에 임시 저장되며, 로그인하면 계정에도 저장됩니다.
소제목 단위로 진행 · 이사야
Olúwa ṣàánú fún wa
Ní ìkérara ohùn rẹ, àwọn ènìyàn sá,
Ìkógun rẹ, ìwọ orílẹ̀-èdè ni a kórè
A gbé Olúwa ga, nítorí pé ó ń gbé ibi gíga,
Òun yóò jẹ́ ìpìlẹ̀ tí ó dájú fún àkókò rẹ
Wò ó, àwọn onígboyà ọkùnrin wọn pohùnréré
Àwọn ojú ọ̀nà ńlá ni a ṣá tì,
Ilẹ̀ ṣọ̀fọ̀ ó sì ṣòfò dànù,
“Ní ìsinsin yìí ni èmi yóò dìde,” ni Olúwa wí.
Ìwọ lóyún ìyàngbò,
A ó jó àwọn ènìyàn run bí eérú;
Ìwọ tí ó wà lọ́nà jíjìn, gbọ́ ohun tí mo ti ṣe;
Ẹ̀rù ba àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ní Sioni;
Ẹni tí ó ń rìn lódodo
Òun náà yóò gbé ní ibi gíga,
Ojú rẹ yóò rí ọba nínú ẹwà rẹ̀
Nínú èrò rẹ ìwọ yóò rántí ẹ̀rù rẹ àtẹ̀yìnwá:
Ìwọ kì yóò rí àwọn agbéraga ènìyàn mọ́,
Gbójú sókè sí Sioni, ìlú àjọ̀dún wa,
Níbẹ̀ ni Olúwa yóò ti jẹ́ alágbára kan fún wa.
Nítorí Olúwa ni onídàájọ́ wa,
Gbogbo okùn rẹ ni ó ti dẹ̀:
Kò sí ẹnikẹ́ni tí ó ń gbé Sioni tí yóò wí pé, “Ara mi kò yá,”