“Kígbe rẹ̀ sókè, má ṣe fàsẹ́yìn.
KO
Copywork
Yoruba OYCB 이사야 58장
성경필사는 빠르게 끝내는 입력 훈련이 아니라, 한 절씩 말씀의 문장과 흐름을 다시 붙드는 시간입니다. 입력 내용은 이 브라우저에 임시 저장되며, 로그인하면 계정에도 저장됩니다.
소제목 단위로 진행 · 이사야
Nítorí ọjọ́ dé ọjọ́ ni wọ́n ń wá mi kiri;
Wọ́n wí pé, ‘Èéṣe tí àwa fi ń gbààwẹ̀,
Àwẹ̀ yín sì parí nínú ìjà àti asọ̀,
Ǹjẹ́ èyí ha ni irú àwẹ̀ tí mo yàn bí,
“Ǹjẹ́ irú àwẹ̀ tí mo ti yàn kọ́ ni èyí:
Kì í ha á ṣe láti pín oúnjẹ yín fún àwọn tí ebi ń pa
Nígbà náà ni ìmọ́lẹ̀ rẹ yóò tàn jáde bí òwúrọ̀
Nígbà yìí ni ẹ̀yin yóò pè, tí Olúwa yóò sì dáhùn;
àti bí ẹ̀yin bá ná ara yín bí owó nítorí àwọn tí ebi ń pa
Olúwa yóò máa tọ́ ọ yín nígbà gbogbo;
Àwọn ènìyàn rẹ yóò tún ahoro àtijọ́ kọ́
“Bí ìwọ bá pa ẹsẹ̀ rẹ mọ́ kúrò nínú bíba ọjọ́ ìsinmi jẹ́,
nígbà náà ni ìwọ yóò ní ayọ̀ nínú Olúwa rẹ,