Ọ̀rọ̀ Olúwa sì tọ̀ mí wá wí pé:
Copywork input for chapter 2 verse 1
Your input is saved to this browser automatically.
“Lọ kí o sì kéde sí etí Jerusalẹmu pé:
Copywork input for chapter 2 verse 2
Your input is saved to this browser automatically.
Israẹli jẹ́ mímọ́ sí Olúwa,
Copywork input for chapter 2 verse 3
Your input is saved to this browser automatically.
Gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa, ẹ̀yin ìdílé Jakọbu
Copywork input for chapter 2 verse 4
Your input is saved to this browser automatically.
Báyìí ni Olúwa wí:
Copywork input for chapter 2 verse 5
Your input is saved to this browser automatically.
Wọn kò béèrè, ‘Níbo ni Olúwa wà,
Copywork input for chapter 2 verse 6
Your input is saved to this browser automatically.
Èmi mú yín wá sí ilẹ̀ ọlọ́ràá
Copywork input for chapter 2 verse 7
Your input is saved to this browser automatically.
Àwọn àlùfáà kò béèrè wí pé,
Copywork input for chapter 2 verse 8
Your input is saved to this browser automatically.
“Nítorí náà, mo fi ẹ̀sùn kàn yín lẹ́ẹ̀kan sí i,”
Copywork input for chapter 2 verse 9
Your input is saved to this browser automatically.
Rékọjá lọ sí erékùṣù àwọn ara Kittimu, kí ẹ sì wò ó,
Copywork input for chapter 2 verse 10
Your input is saved to this browser automatically.
Orílẹ̀-èdè kan ha á pa ọlọ́run rẹ̀ dà?
Copywork input for chapter 2 verse 11
Your input is saved to this browser automatically.
Àwọn ènìyàn mi ti dẹ́ṣẹ̀ méjì
Copywork input for chapter 2 verse 12
Your input is saved to this browser automatically.
“Àwọn ènìyàn mi ti dẹ́ṣẹ̀ méjì,
Copywork input for chapter 2 verse 13
Your input is saved to this browser automatically.
Israẹli ha á jẹ́ ọmọ ọ̀dọ̀ ẹrú nípa ìbí?
Copywork input for chapter 2 verse 14
Your input is saved to this browser automatically.
Àwọn kìnnìún ké ramúramù;
Copywork input for chapter 2 verse 15
Your input is saved to this browser automatically.
Bákan náà, àwọn ọkùnrin Memfisi àti Tafanesi
Copywork input for chapter 2 verse 16
Your input is saved to this browser automatically.
Ẹ̀yin kò ha a ti fa èyí sórí ara yín
Copywork input for chapter 2 verse 17
Your input is saved to this browser automatically.
Kí ló dé tí o ṣe wá lọ Ejibiti
Copywork input for chapter 2 verse 18
Your input is saved to this browser automatically.
Iṣẹ́ búburú yín yóò fìyà jẹ yín
Copywork input for chapter 2 verse 19
Your input is saved to this browser automatically.
“Nígbà àtijọ́, o ti fọ́ àjàgà rẹ sọnù,
Copywork input for chapter 2 verse 20
Your input is saved to this browser automatically.
Èmi ti gbìn ọ́ gẹ́gẹ́ bí àjàrà ọ̀tọ̀,
Copywork input for chapter 2 verse 21
Your input is saved to this browser automatically.
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé o wẹ ara rẹ pẹ̀lú sódà
Copywork input for chapter 2 verse 22
Your input is saved to this browser automatically.
“Báwo ni ìwọ ṣe wí pé, ‘Èmi kò ṣe aláìmọ́,
Copywork input for chapter 2 verse 23
Your input is saved to this browser automatically.
Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ igbó tí ń gbé aginjù
Copywork input for chapter 2 verse 24
Your input is saved to this browser automatically.
Dá ẹsẹ̀ dúró láìwọ bàtà,
Copywork input for chapter 2 verse 25
Your input is saved to this browser automatically.
“Gẹ́gẹ́ bí a ṣe ń dójútì olè nígbà tí a bá mú u,
Copywork input for chapter 2 verse 26
Your input is saved to this browser automatically.
Wọ́n sọ fún igi pé, ‘Ìwọ ni baba mi,’
Copywork input for chapter 2 verse 27
Your input is saved to this browser automatically.
Níbo wá ni àwọn ọlọ́run tí ẹ ṣe fúnra yín ha a wà?
Copywork input for chapter 2 verse 28
Your input is saved to this browser automatically.
“Kí ló dé tí o ṣe wá ń fi ẹ̀sùn kàn mí?
Copywork input for chapter 2 verse 29
Your input is saved to this browser automatically.
“Nínú asán mo fìyà jẹ àwọn ènìyàn yín,
Copywork input for chapter 2 verse 30
Your input is saved to this browser automatically.
“Ẹ̀yin ìran yìí, ẹ kíyèsi ọ̀rọ̀ Olúwa:
Copywork input for chapter 2 verse 31
Your input is saved to this browser automatically.
Wúńdíá ha le gbàgbé ohun ọ̀ṣọ́ rẹ̀,
Copywork input for chapter 2 verse 32
Your input is saved to this browser automatically.
Ìwọ ti jẹ́ ọlọ́gbọ́n tó nípa ọ̀rọ̀ ìfẹ́!
Copywork input for chapter 2 verse 33
Your input is saved to this browser automatically.
Lórí aṣọ rẹ ni wọ́n bá
Copywork input for chapter 2 verse 34
Your input is saved to this browser automatically.
ìwọ sọ wí pé, ‘Èmi jẹ́ aláìṣẹ̀;
Copywork input for chapter 2 verse 35
Your input is saved to this browser automatically.
Èéṣe tí ìwọ fi ń lọ káàkiri
Copywork input for chapter 2 verse 36
Your input is saved to this browser automatically.
Ìwọ yóò sì fi ibẹ̀ sílẹ̀
Copywork input for chapter 2 verse 37