Èmi fẹ́ràn Olúwa, nítorí ó gbọ́ ohùn mi;
KO
Copywork
Yoruba OYCB 시편 116장
성경필사는 빠르게 끝내는 입력 훈련이 아니라, 한 절씩 말씀의 문장과 흐름을 다시 붙드는 시간입니다. 입력 내용은 이 브라우저에 임시 저장되며, 로그인하면 계정에도 저장됩니다.
소제목 단위로 진행 · 시편
Nítorí ó yí etí rẹ̀ padà sí mi,
Okùn ikú yí mi ká,
Nígbà náà ni mo ké pe orúkọ Olúwa:
Olúwa ní oore-ọ̀fẹ́, ó sì ní òdodo;
Olúwa pa àwọn ọlọ́kàn fífúyẹ́ mọ́
Padà, ìwọ ọkàn mi, sí ibi ìsinmi rẹ,
Nítorí ìwọ, Olúwa, ti gba ọkàn mi
nítorí èmi yóò máa rìn níwájú Olúwa
Èmi gbàgbọ́; nítorí náà mo wí pé,
Àti nínú ìdààmú mi mo wí pé,
Kí ni èmi yóò san fún Olúwa
Èmi yóò gbé ago ìgbàlà sókè
Èmi yóò mú ìlérí mi ṣẹ sí Olúwa
Iyebíye ní ojú Olúwa
Olúwa, nítòótọ́ ìránṣẹ́ rẹ ni mo jẹ́;
Èmi yóò rú ẹbọ ọpẹ́ sí ọ
Èmi yóò mú ìlérí mi sẹ sí Olúwa
nínú àgbàlá ilé Olúwa