성경 읽기

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · 누가복음 1장

대표 구절

Ọ̀pọ̀ ènìyàn ni ó ti dáwọ́lé títo àwọn nǹkan wọ̀n-ọn-nì jọ lẹ́sẹẹsẹ, èyí tí ó ti múlẹ̀ ṣinṣin láàrín wa, 눅 1:1

다음

본문 이동

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · 누가복음 1장

구약

검색

본문 검색

원어 검색 Strong · lemma · 뜻

버전 범위

본문 범위

설정

보기 옵션

사이트 언어

메뉴, 버튼, 안내문 같은 사이트 UI 문구가 선택한 언어로 표시됩니다.

화면 테마

사이트 디자인

사이트 전체의 레이아웃과 분위기를 바꿉니다. 읽기 화면 디자인은 본문 내부 스타일만 바꿉니다.

읽기 화면 디자인

상세 설정

현재 scripture.how 기본 색감입니다.

선택한 스타일은 이 브라우저에 저장됩니다. 로그인하면 서버에 저장할 수 있습니다.

상단 배경

성경 장면은 이 장에 생성된 hero 이미지를 사용합니다. 아직 이미지가 없으면 기본 배경으로 표시됩니다.

Hero 전환

구절 버튼 표시

선택 시 표시는 PC에서는 구절에 마우스를 올릴 때, 모바일에서는 구절을 선택할 때 자료/멀티/댓글 버튼을 보여줍니다.

글자 크기

글꼴

원어 보기

오른쪽 버튼은 정렬된 단어를 카드(원어사전)로 표시하고, 구절 아래는 모든 원어 토큰을 인라인 표시합니다.

원어 검색 열기

원어 검색

이 원어가 등장하는 모든 구절

불러오는 중...

불러오는 중...

구절 자료

원어, 관주, 주석서, 성경노트, 댓글을 한 곳에서 봅니다.

원어 버튼을 눌러 불러옵니다.

단어를 선택하세요.

멀티성경

현재 절을 멀티성경 설정에 따라 비교합니다.

구절의 멀티성경 버튼을 눌러 불러옵니다.

관주

구절의 관련 성경 본문

불러오는 중...

연관 구절

병행 구절 본문

불러오는 중...

원어사전

구절의 원어 단어

불러오는 중...

단어를 선택하세요.

이미지

성경노트 안내

현재 성경노트 작성자가 함께 읽도록 정리한 색상 의미, 칼럼, 개념사전, 서식 용어를 확인할 수 있습니다.

역본 소개

누가복음 읽기 통계

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

이 책 (누가복음)

전체 장수
24장
전체 절수
1,149절
현재 장
1 / 24장
이 장 절수
80절
장 진행율4.2%
절 진행율 (이 장까지)7%

성경 전체 (창세기부터)

현재 장
974 / 1,189장
전체 절수
31,087절
전체 장 진행율81.9%
전체 절 진행율 (이 장까지)80.3%

성경노트 안내

선택된 성경노트의 필독 정보입니다.

하나님/선

하나님으로부터 오는 진리와 생명의 방향성을 의미합니다. 성경에서 하나님, 말씀, 진리, 생명, 빛, 지혜, 하나님 나라 등은 서로 연결된 본질과 방향성을 나타내는 표현들로 설명됩니다. 성경은 이러한 요소들을 단순히 분리된 개념으로만 설명하지 않고, 서로 연결된 하나의 흐름과 방향성으로 표현합니다. 예를 들어: 진리는 생명과 연결되며 빛은 하나님께 속한 길로 표현되고 말씀에 순종하는 것은 하나님 나라에 속한 삶으로 설명됩니다. 따라서 이 색상은 하나님께 속한 진리와 생명의 방향성과 질서를 나타내는 표현들을 포함합니다.

사탄/악

하나님을 대적하는 거짓과 사망의 방향성을 의미합니다. 성경은 사탄, 거짓, 미혹, 어둠, 사망, 불법, 세상 권세 등을 단순히 분리된 개념으로만 설명하지 않고, 서로 연결된 하나의 방향성과 본질로 묘사합니다. 인간은 이를 존재, 거짓된 가르침, 속성, 결과, 지배 체계 등으로 구분하여 인식하지만, 성경은 이러한 요소들을 서로 연결된 의미로 표현합니다. 예를 들어: 거짓은 사탄에게 속한 것으로 표현되며 어둠은 사망과 연결되고 불법은 하나님을 대적하는 길로 설명되며 세상 권세는 미혹과 멸망의 체계로 묘사됩니다. 따라서 이 색상은 하나님을 거스르는 방향성과 질서를 따르는 표현들을 포함합니다.

선을 따르는 사람

본문의 인물이나 공동체를 선을 따르는 사람의 관점에서 해석할 때 사용합니다. 이 색상은 인물 전체에 대한 최종 판정이 아니라, 해당 구절에서 드러나는 방향성이 하나님께 속한 진리, 생명, 빛, 순종의 흐름으로 읽히는 경우를 표시합니다. 같은 인물이라도 다른 문맥에서는 연약함이나 세상성을 드러낼 수 있으므로, 파란색은 영구 신분표가 아니라 본문 단위의 해석 관점입니다. 특히 어떤 구절은 파란색 관점과 녹색 관점이 모두 가능할 수 있으며, 그런 경우에는 청녹색의 양면 관점으로 표시할 수 있습니다.

양면 관점

같은 구절이나 표현을 파란색 관점과 녹색 관점 모두로 해석할 수 있을 때 사용합니다. 이는 의미 자체가 불명확하다는 뜻이 아니라, 본문을 바라보는 관점에 따라 선을 따르는 사람의 연약함으로도, 세상성이나 육신을 따르는 모습으로도 읽힐 수 있음을 나타냅니다. 따라서 청녹색은 별도의 사람 분류나 최종 판정이 아닙니다. 해석자가 실제로 파란색으로 표시할지 녹색으로 표시할지 고민하게 되는 지점, 두 관점이 병존하는 지점을 표시합니다. 예를 들어 믿음의 방향은 선을 향하지만 본문에서는 육신적 연약함이 두드러지는 경우, 또는 한 표현이 선한 양심의 흔들림으로도 세상성의 작용으로도 읽히는 경우에 사용할 수 있습니다.

세상을 따르는 사람

본문의 인물이나 공동체를 세상, 육신, 불순종의 방향을 따르는 관점에서 해석할 때 사용합니다. 이 색상은 인물 전체를 단정하기 위한 표시가 아니라, 해당 구절에서 드러나는 방향성이 거짓, 어둠, 욕망, 불법, 세상 권세의 흐름으로 읽히는 경우를 표시합니다. 같은 인물이나 같은 표현이라도 문맥에 따라 선을 따르는 사람의 연약함으로 읽힐 수도 있고, 세상성을 따르는 모습으로 읽힐 수도 있습니다. 그런 경우에는 녹색으로 확정하기보다 청녹색의 양면 관점으로 표시할 수 있습니다. 따라서 녹색은 파란색의 반대편 관점을 나타내지만, 모든 연약함을 곧바로 악으로 단정하는 색상은 아닙니다.

강조

본문 흐름에서 특별히 강조할 표현을 표시합니다.

중립

선과 악의 축과 직접 관련 없는 중립적 의미를 나타냅니다. 성경에는 선과 악의 방향성을 직접 나타내기보다, 단순한 배경 정보나 역사적 사실, 일반적인 표현 등으로 사용되는 요소들도 존재합니다. 인간은 이를 지명, 시간, 역사적 사건, 일반 명사, 단순 상황 설명 등으로 구분하여 인식하며, 이러한 표현들은 문맥 설명을 위한 역할로 사용됩니다. 또한 문맥상 선과 악의 의미를 직접 부여하지 않는 경우에는, 특정 인물이나 민족을 설명하는 표현도 중립적으로 사용될 수 있습니다. 예를 들어: 특정 지역이나 시대를 설명하는 표현이 사용되기도 하며 선과 악의 의미를 직접 포함하지 않는 일반적인 사물이나 상황이 묘사되기도 하고 단순한 배경 정보나 역사적 흐름을 설명하는 표현으로 사용되기도 합니다. 또한 문맥에 따라 "이방인", "유대인", "로마인" 등의 표현 역시 선악의 의미를 직접 나타내지 않는 경우에는 중립적으로 사용될 수 있습니다. 따라서 이 색상은 선과 악의 방향성을 직접 나타내지 않는 중립적 표현들을 포함합니다.

Dedication to Theophilus

1
Ọ̀pọ̀ ènìyàn ni ó ti dáwọ́lé títo àwọn nǹkan wọ̀n-ọn-nì jọ lẹ́sẹẹsẹ, èyí tí ó ti múlẹ̀ ṣinṣin láàrín wa, 카드
원어 11개 불러오는 중...
2
àní gẹ́gẹ́ bí àwọn ìránṣẹ́ ọ̀rọ̀ náà, tí ó ṣe ojú wọn láti ìbẹ̀rẹ̀ ti fi lé wa lọ́wọ́. 카드
원어 12개 불러오는 중...
3
Nítorí náà, ó sì yẹ fún èmi pẹ̀lú, láti kọ̀wé sí ọ lẹ́sẹẹsẹ bí mo ti wádìí ohun gbogbo fínní fínní sí láti ìpilẹ̀ṣẹ̀, Teofilu ọlọ́lá jùlọ, 카드
원어 11개 불러오는 중...
4
kí ìwọ kí ó le mọ òtítọ́ ohun wọ̀n-ọn-nì, tí a ti kọ́ ọ. 카드
원어 8개 불러오는 중...

The Birth of John the Baptist Foretold

5
Nígbà ọjọ́ Herodu ọba Judea, àlùfáà kan wà, láti ìran Abijah, orúkọ rẹ̀ a máa jẹ́ Sekariah: aya rẹ̀ sì ṣe ọ̀kan nínú àwọn ọmọbìnrin Aaroni, orúkọ rẹ̀ a sì máa jẹ́ Elisabeti. 카드
원어 29개 불러오는 중...
6
Àwọn méjèèjì sì ṣe olódodo níwájú Ọlọ́run, wọ́n ń rìn ní gbogbo òfin àti ìlànà Olúwa ní àìlẹ́gàn. 카드
원어 17개 불러오는 중...
7
Ṣùgbọ́n wọn kò ní ọmọ, nítorí tí Elisabeti yàgàn; àwọn méjèèjì sì di arúgbó. 카드
원어 18개 불러오는 중...
8
Ó sì ṣe, nígbà tí ó ń ṣe iṣẹ́ àlùfáà níwájú Ọlọ́run ni àkókò tirẹ̀. 카드
원어 15개 불러오는 중...
9
Bí ìṣe àwọn àlùfáà, ipa tirẹ̀ ni láti máa fi tùràrí jóná, nígbà tí ó bá wọ inú tẹmpili Olúwa lọ. 카드
원어 14개 불러오는 중...
10
Gbogbo ìjọ àwọn ènìyàn sì ń gbàdúrà lóde ní àkókò sísun tùràrí. 카드
원어 13개 불러오는 중...
11
Angẹli Olúwa kan sì fi ara hàn án, ó dúró ní apá ọ̀tún pẹpẹ tùràrí. 카드
원어 12개 불러오는 중...
12
Nígbà tí Sekariah sì rí i, orí rẹ̀ wú, ẹ̀rù sì bà á. 카드
원어 9개 불러오는 중...
13
Ṣùgbọ́n angẹli náà wí fún un pé, “Má bẹ̀rù, Sekariah: nítorí tí àdúrà rẹ gbà; Elisabeti aya rẹ yóò sì bí ọmọkùnrin kan fún ọ, ìwọ ó sì sọ orúkọ rẹ̀ ní Johanu. 카드
원어 28개 불러오는 중...
14
Òun yóò sì jẹ́ ayọ̀ àti ìdùnnú fún ọ, ènìyàn púpọ̀ yóò sì yọ̀ sí ìbí rẹ. 카드
원어 13개 불러오는 중...
15
Nítorí òun ó pọ̀ níwájú Olúwa, kì yóò sì mu ọtí wáìnì, bẹ́ẹ̀ ni kì yóò sì mu ọtí líle; yóò sì kún fún Ẹ̀mí Mímọ́ àní láti inú ìyá rẹ̀ wá. 카드
원어 22개 불러오는 중...
16
Òun ó sì yí ènìyàn púpọ̀ padà nínú àwọn ọmọ Israẹli sí Olúwa Ọlọ́run wọn. 카드
원어 11개 불러오는 중...
17
Ẹ̀mí àti agbára Elijah ni Olúwa yóò sì fi ṣáájú rẹ̀ lọ, láti pa ọkàn àwọn baba dà sí ti àwọn ọmọ, àti ti àwọn aláìgbọ́ràn sí ọgbọ́n àwọn olóòtítọ́; kí ó le pèsè àwọn ènìyàn tí a múra sílẹ̀ de Olúwa.” 카드
원어 24개 불러오는 중...
18
Sekariah sì wí fún angẹli náà pé, “Àmì wo ni èmi ó fi mọ èyí? Èmi sá ti di àgbà, àti Elisabeti aya mi sì di arúgbó.” 카드
원어 23개 불러오는 중...
19
Angẹli náà sì dáhùn ó wí fún un pé, “Èmi ni Gabrieli, tí máa ń dúró níwájú Ọlọ́run; èmi ni a rán wá láti sọ fún ọ, àti láti mú ìròyìn ayọ̀ wọ̀nyí fún ọ wá. 카드
원어 23개 불러오는 중...
20
Sì kíyèsi i, ìwọ ó yadi, ìwọ kì yóò sì le fọhùn, títí ọjọ́ náà tí nǹkan wọ̀nyí yóò fi ṣẹ, nítorí ìwọ kò gba ọ̀rọ̀ mi gbọ́ tí yóò ṣẹ ní àkókò wọn.” 카드
원어 26개 불러오는 중...
21
Àwọn ènìyàn sì ń dúró de Sekariah, ẹnu sì yà wọ́n nítorí tí ó pẹ́ nínú tẹmpili. 카드
원어 16개 불러오는 중...
22
Nígbà tí ó sì jáde wá, òun kò le bá wọn sọ̀rọ̀. Wọn sì kíyèsi wí pé ó ti rí ìran nínú tẹmpili, ó sì ń ṣe àpẹẹrẹ sí wọn, nítorí tí ó yadi. 카드
원어 22개 불러오는 중...
23
Ó sì ṣe, nígbà tí ọjọ́ iṣẹ́ ìsìn rẹ̀ pé, ó lọ sí ilé rẹ̀. 카드
원어 14개 불러오는 중...
24
Lẹ́yìn èyí ni Elisabeti aya rẹ̀ lóyún, ó sì fi ara rẹ̀ pamọ́ ní oṣù márùn-ún, 카드
원어 16개 불러오는 중...
25
Ó sì wí pé, “Báyìí ni Olúwa ṣe fún mi ní ọjọ́ tí ó síjú wò mí, láti mú ẹ̀gàn mi kúrò láàrín àwọn ènìyàn.” 카드
원어 16개 불러오는 중...

The Birth of Jesus Foretold

26
Ní oṣù kẹfà Ọlọ́run sì rán angẹli Gabrieli sí ìlú kan ní Galili, tí à ń pè ní Nasareti, 카드
원어 20개 불러오는 중...
27
sí wúńdíá kan tí a ṣèlérí láti fẹ́ fún ọkùnrin kan, tí a ń pè ní Josẹfu, ti ìdílé Dafidi; orúkọ wúńdíá náà a sì máa jẹ́ Maria. 카드
원어 16개 불러오는 중...
28
Angẹli náà sì tọ̀ ọ́ wá, ó ní, “Àlàáfíà fun ọ, ìwọ ẹni tí a kọjú sí ṣe ní oore, Olúwa ń bẹ pẹ̀lú rẹ.” 카드
원어 17개 불러오는 중...
29
Ṣùgbọ́n ọkàn Maria kò lélẹ̀ nítorí ọ̀rọ̀ náà, ó sì rò nínú ara rẹ̀ pé, irú kíkí kín ni èyí. 카드
원어 15개 불러오는 중...
30
Ṣùgbọ́n angẹli náà wí fún un pé, “Má bẹ̀rù, Maria, nítorí ìwọ ti rí ojúrere lọ́dọ̀ Ọlọ́run. 카드
원어 14개 불러오는 중...
31
Ìwọ yóò lóyún nínú rẹ, ìwọ ó sì bí ọmọkùnrin kan, ìwọ ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Jesu. 카드
원어 14개 불러오는 중...
32
Òun ó pọ̀, ọmọ Ọ̀gá-ògo jùlọ ni a ó sì máa pè é, Olúwa Ọlọ́run yóò sì fi ìtẹ́ Dafidi baba rẹ̀ fún. 카드
원어 19개 불러오는 중...
33
Yóò sì jẹ ọba lórí ilé Jakọbu títí láé; ìjọba rẹ̀ kì yóò sì ní ìpẹ̀kun.” 카드
원어 16개 불러오는 중...
34
Nígbà náà ni Maria béèrè lọ́wọ́ angẹli náà pé, “Èyí yóò ha ti ṣe rí bẹ́ẹ̀, nígbà tí èmi kò tí ì mọ ọkùnrin.” 카드
원어 13개 불러오는 중...
35
Angẹli náà sì dáhùn ó sì wí fún un pé, “Ẹ̀mí Mímọ́ yóò tọ̀ ọ́ wá, agbára Ọ̀gá-ògo jùlọ yóò síji bò ọ́. Nítorí náà ohun mímọ́ tí a ó ti inú rẹ bí, Ọmọ Ọlọ́run ni a ó máa pè é. 카드
원어 24개 불러오는 중...
36
Sì kíyèsi i, Elisabeti ìbátan rẹ náà yóò sì ní ọmọkùnrin kan ní ògbólógbòó rẹ̀, èyí sì ni oṣù kẹfà fún ẹni tí à ń pè ní àgàn. 카드
원어 22개 불러오는 중...
37
Nítorí kò sí ohun tí Ọlọ́run kò le ṣe.” 카드
원어 8개 불러오는 중...
38
Maria sì dáhùn wí pé, “Wò ó ọmọ ọ̀dọ̀ Olúwa; kí ó rí fún mi gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ rẹ.” Angẹli náà sì fi í sílẹ̀ lọ. 카드
원어 19개 불러오는 중...

Mary Visits Elizabeth

39
Ní àkókò náà ni Maria sì dìde, ó lọ kánkán sí ilẹ̀ òkè, sí ìlú kan ní Judea; 카드
원어 16개 불러오는 중...
40
Ó sì wọ ilé Sekariah lọ ó sì kí Elisabeti. 카드
원어 10개 불러오는 중...
41
Ó sì ṣe, nígbà tí Elisabeti gbọ́ kíkí Maria, ọlẹ̀ sọ nínú rẹ̀; Elisabeti sì kún fún Ẹ̀mí Mímọ́, 카드
원어 23개 불러오는 중...
42
Ó sì ké ní ohùn rara, ó sì wí pé, “Alábùkún fún ni ìwọ nínú àwọn obìnrin, alábùkún fún sì ni ọmọ tí ìwọ yóò bí. 카드
원어 17개 불러오는 중...
43
Èéṣe tí èmi fi rí irú ojúrere yìí, tí ìyá Olúwa mi ìbá fi tọ̀ mí wá? 카드
원어 13개 불러오는 중...
44
Sá wò ó, bí ohùn kíkí rẹ ti bọ́ sí mi ní etí, ọlẹ̀ sọ nínú mi fún ayọ̀. 카드
원어 22개 불러오는 중...
45
Alábùkún fún sì ni ẹni tí ó gbàgbọ́, nítorí nǹkan wọ̀nyí tí a ti sọ fún un láti ọ̀dọ̀ Olúwa wá yóò ṣẹ.” 카드
원어 12개 불러오는 중...

Mary's Song of Praise: The Magnificat

46
Maria sì dáhùn, ó ní: 카드
원어 9개 불러오는 중...
47
Ẹ̀mí mi sì yọ̀ sí Ọlọ́run Olùgbàlà mi. 카드
원어 11개 불러오는 중...
48
Nítorí tí ó síjú wo ìwà ìrẹ̀lẹ̀ 카드
원어 18개 불러오는 중...
49
Nítorí ẹni tí ó ní agbára ti ṣe ohun tí ó tóbi fún mi; 카드
원어 11개 불러오는 중...
50
Àánú rẹ̀ sì ń bẹ fún àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀, 카드
원어 11개 불러오는 중...
51
Ó ti fi agbára hàn ní apá rẹ̀; 카드
원어 10개 불러오는 중...
52
Ó ti mú àwọn alágbára kúrò lórí ìtẹ́ wọn, 카드
원어 7개 불러오는 중...
53
Ó ti fi ohun tí ó dára kún àwọn tí ebi ń pa 카드
원어 7개 불러오는 중...
54
Ó ti ran Israẹli ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ lọ́wọ́, 카드
원어 6개 불러오는 중...
55
sí Abrahamu àti àwọn ìran rẹ̀ láéláé, baba wa, 카드
원어 15개 불러오는 중...
56
Maria sì jókòó tì Elisabeti níwọ̀n oṣù mẹ́ta, ó sì padà lọ sí ilé rẹ̀. 카드
원어 14개 불러오는 중...

The Birth of John the Baptist

57
Nígbà tí ọjọ́ Elisabeti pé tí yóò bí; ó sì bí ọmọkùnrin kan. 카드
원어 12개 불러오는 중...
58
Àwọn aládùúgbò, àti àwọn ìbátan rẹ̀ gbọ́ bí Olúwa ti fi àánú ńlá hàn fún un, wọ́n sì bá a yọ̀. 카드
원어 19개 불러오는 중...
59
Ó sì ṣe, ní ọjọ́ kẹjọ wọ́n wá láti kọ ọmọ náà nílà; wọ́n sì fẹ́ sọ orúkọ rẹ̀ ní Sekariah, gẹ́gẹ́ bí orúkọ baba rẹ̀. 카드
원어 21개 불러오는 중...
60
Ìyá rẹ̀ sì dáhùn, ó ní, “Bẹ́ẹ̀ kọ́! Johanu ni a ó pè é.” 카드
원어 10개 불러오는 중...
61
Wọ́n sì wí fún un pé, “Kò sí ọ̀kan nínú àwọn ará rẹ̀ tí à ń pè ní orúkọ yìí.” 카드
원어 16개 불러오는 중...
62
Wọ́n sì ṣe àpẹẹrẹ sí baba rẹ̀, bí ó ti ń fẹ́ kí a pè é. 카드
원어 11개 불러오는 중...
63
Ó sì béèrè fún wàláà, ó sì kọ ọ wí pé, “Johanu ni orúkọ rẹ̀.” Ẹnu sì ya gbogbo wọn. 카드
원어 13개 불러오는 중...
64
Ẹnu rẹ̀ sì ṣí lọ́gán, okùn ahọ́n rẹ̀ sì tú, ó sì sọ̀rọ̀, ó sì ń yin Ọlọ́run. 카드
원어 15개 불러오는 중...
65
Ẹ̀rù sì ba gbogbo àwọn tí ń bẹ ní agbègbè wọn, a sì ròyìn gbogbo nǹkan wọ̀nyí ká gbogbo ilẹ̀ òkè Judea. 카드
원어 20개 불러오는 중...
66
Ó sì jẹ́ ohun ìyanu fún gbogbo àwọn tí ó gbọ́ nípa rẹ̀, wọ́n sì tò ó sínú ọkàn wọn, wọ́n ń wí pé, “Irú-ọmọ kín ni èyí yóò jẹ́?” Nítorí tí ọwọ́ Olúwa wà pẹ̀lú rẹ̀. 카드
원어 23개 불러오는 중...

Zechariah's Prophecy

67
Sekariah baba rẹ̀ sì kún fún Ẹ̀mí Mímọ́, ó sì sọtẹ́lẹ̀, ó ní: 카드
원어 11개 불러오는 중...
68
“Olùbùkún ni Olúwa Ọlọ́run Israẹli; 카드
원어 14개 불러오는 중...
69
Ó sì ti gbé ìwo ìgbàlà sókè fún wa 카드
원어 12개 불러오는 중...
70
(bí ó ti sọtẹ́lẹ̀ láti ẹnu àwọn wòlíì rẹ̀ mímọ́ tipẹ́tipẹ́), 카드
원어 11개 불러오는 중...
71
Pé, a ó gbà wá là lọ́wọ́ 카드
원어 11개 불러오는 중...
72
Láti ṣe àánú tí ó ṣèlérí fún àwọn baba wa, 카드
원어 11개 불러오는 중...
73
ìbúra tí ó ti bú fún Abrahamu baba wa, 카드
원어 8개 불러오는 중...
74
láti gbà wá lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wa, 카드
원어 9개 불러오는 중...
75
ni ìwà mímọ́ àti ní òdodo níwájú rẹ̀, ní ọjọ́ ayé wa gbogbo. 카드
원어 12개 불러오는 중...
76
“Àti ìwọ, ọmọ mi, wòlíì Ọ̀gá-ògo jùlọ ni a ó máa pè ọ́: 카드
원어 15개 불러오는 중...
77
láti fi ìmọ̀ ìgbàlà fún àwọn ènìyàn rẹ̀ 카드
원어 11개 불러오는 중...
78
nítorí ìyọ́nú Ọlọ́run wà; 카드
원어 12개 불러오는 중...
79
Láti fi ìmọ́lẹ̀ fún àwọn tí ó jókòó ní 카드
원어 16개 불러오는 중...
80
Ọmọ náà sì dàgbà, ó sì le ní ọkàn, ó sì ń gbé ní ijù títí ó fi di ọjọ́ ìfihàn rẹ̀ fún Israẹli. 카드
원어 19개 불러오는 중...
주석서 누가복음 1장
Matthew Henry's Complete Commentary · Matthew Henry (1714) 퍼블릭 도메인 (PD) 출처

장별/책 단위 주석

책 개요, 장 서론, 여러 장 범위처럼 특정 절이 아닌 단위에 연결된 주석입니다.

장 서론

이 복음서 기자가 우리에게 전해 주는, 더 정확히 말하면 하나님께서...

절별/절범위 주석

현재 장의 특정 절이나 절 범위에 직접 연결된 주석입니다.

1-4 The Evangelist's Preface

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

5-25 The Appearance of an Angel to Zacharias; The Birth of John Foretold; The Unbelief of Zacharias

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

26-38 The Birth of Christ Foretold

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

39-56 The Interview of Mary and Elisabeth; The Song of Mary

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

57-66 The Birth of John the Baptist

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

67-80 The Song of Zacharias

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

Jamieson-Fausset-Brown Commentary Critical and Explanatory on the Whole Bible · Robert Jamieson, A. R. Fausset, David Brown (1871) 퍼블릭 도메인 (PD) 출처

장별/책 단위 주석

책 개요, 장 서론, 여러 장 범위처럼 특정 절이 아닌 단위에 연결된 주석입니다.

장 서론

Introduction

절별/절범위 주석

현재 장의 특정 절이나 절 범위에 직접 연결된 주석입니다.

1 Lu 1:1-4.

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

2 2. 처음부터

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

3 3. 그 근원부터

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

4 4. 알게 하려 함이로라

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

5 Lu 1:5-25.

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

6 6. 계명과 규례

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

7 7. 아브라함과 사라, 이삭과 리브가, 엘가나와 한나, 마노아와 그의...

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

9 9. 제비를 뽑아 분향하게 되었더니

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

10 10. 밖에서 기도하더니

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

11 11. 오른쪽

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

13 13. 네 간구함이 들린지라

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

14 14. 기뻐하리니

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

15 15. 주 앞에 큰 자가 되며

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

16 16, 17. 그는 엘리야와 같은 종교적·도덕적 개혁자가 될 것이었다말...

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

17 17. 그 앞에

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

18 18. 무엇으로 알리이까

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

19 19. 가브리엘

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

20 20. 말 못하는 자

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

21 21. 기다리며

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

22 22. 말을 못하니

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

24 24. 다섯 달 동안 숨어 있으며

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

26 Lu 1:26-38.

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

28 28. 은혜를 받은 자여

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

31 31. 천사는 의도적으로 이사야의 유명한 예언사 7:14에 자신의 언어...

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

32 32, 33. 이것은 사 9:6, 7에 있는 숭고한 예언의 메아리에 불과하다

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

34 34. 어찌 이 일이 있으리이까

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

35 35. 성령

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

36 36. 네 친족

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

37 37. 대저

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

38 38. 그런 상황에서 보인 놀라운 믿음이다!

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

39 Lu 1:39-56.

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

40 40. 엘리사벳에게 문안하니

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

41 41. 아이가 뛰노는지라

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

42 42-44. 여기서 우리는 시기를 뛰어넘는 얼마나 아름다운 우월성을 보...

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

43 43. "내 주의 어머니"이지 "나의 여주인"이 아니다눅 20:42; 요 20:2...

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

45 45. 암묵적이고 섬세하게 자기 남편과 대조하면서, 처녀의 온전한 믿...

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

46 46-55. 장엄한 찬가이다. 같은 상황에서 나온 한나의 옛 노래의 가락...

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

47 47. 내 구주

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

54 54. 도우사

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

55 55. 우리 조상에게 말씀하신 것과 같이

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

56 56. 석 달쯤 함께 있다가

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

57 Lu 1:57-80.

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

59 59. 팔 일이 되매

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

62 62. 손짓하여

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

63 63. 다 놀랍게 여기더라

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

64 64. 곧 입이 열리고

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

65 65. 두려워하더라

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

66 66. 주의 손이 그와 함께 하심이러라

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

68 68-79. 이 고귀한 신적 노래의 폭발 속에는 자기 아이에 대한 말이...

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

69 69. 구원의 뿔

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

70 70. 창세 전부터

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

72 72. 약속하신 긍휼 . . . 그의 거룩한 언약

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

73 73. 우리 조상 아브라함에게 하신 맹세

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

74 74, 75. 우리에게 주사

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

76 76-79. 여기에는 이 노래의 마지막 메아리들이 있다. 이 닫는 음들은...

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

77 77. 구원을 알게 하리니

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

78 78. 우리 하나님의 긍휼로

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

79 79. 사 9:2; 마 4:13-17과 비교하라

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

80 80. 아이가 자라며

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

원문 주석서는 저작권 보호 기간이 만료된 공개 도메인 저작입니다. scripture.how가 제공하는 한글 번역·편집·구조화 콘텐츠에는 별도 이용 조건이 적용됩니다.

주석

선택한 구절의 주석서 내용