Nísinsin yìí, kó àwọn ọ̀wọ́ ogun rẹ jọ,
JA
Copywork
Yoruba OYCB Micah 5장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Micah
“Ṣùgbọ́n ìwọ, Bẹtilẹhẹmu Efrata,
Nítorí náà Israẹli yóò di kíkọ̀sílẹ̀ pátápátá
Òun yóò sì dúró,
Òun yóò sì jẹ́ àlàáfíà wọn.
Wọn yóò sì fi idà pa ilẹ̀ Asiria run,
Ìyókù Jakọbu yóò sì wà
Ìyókù Jakọbu yóò sì wà láàrín àwọn aláìkọlà
A ó gbé ọwọ́ rẹ̀ sókè ní ìṣẹ́gun lórí àwọn ọ̀tá rẹ̀,
“Ní ọjọ́ náà,” ni Olúwa wí,
Èmi yóò sì pa ilẹ̀ ìlú ńlá rẹ̀ run,
Èmi yóò gé ìwà àjẹ́ kúrò lọ́wọ́ rẹ̀,
Èmi yóò pa àwọn ère fínfín rẹ̀ run,
Èmi yóò fa ère Aṣerah tu kúrò láàrín rẹ̀,
Èmi yóò gbẹ̀san ní ìbínú àti ìrunú