Ìran ti Obadiah.
JA
Copywork
Yoruba OYCB Obadiah 1장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
“Kíyèsi i, Èmi yóò sọ ọ́ di kékeré láàrín àwọn kèfèrí;
Ìgbéraga àyà rẹ ti tàn ọ́ jẹ,
Bí ìwọ tilẹ̀ gbé ara rẹ ga bí ẹyẹ idì,
“Bí àwọn olè tọ̀ ọ́ wá,
Báwo ni a ṣe ṣe àwárí nǹkan Esau,
Gbogbo àwọn ẹni ìmùlẹ̀ rẹ
Olúwa wí pé, “Ní ọjọ́ náà,
A ó ṣe ẹ̀rù ba àwọn jagunjagun rẹ, ìwọ Temani,
Nítorí ìwà ipá sí Jakọbu arákùnrin rẹ,
Ní ọjọ́ tí ìwọ dúró ní apá kan,
Ìwọ kì bá tí fi ojú kéré arákùnrin rẹ,
Ìwọ kì bá tí wọ inú ibodè àwọn ènìyàn mi lọ,
Ìwọ kì bá tí dúró ní ìkóríta ọ̀nà
“Nítorí ọjọ́ Olúwa súnmọ́ etílé
Gẹ́gẹ́ bí ìwọ̀ ṣe mu lórí òkè mímọ́ mi,
Ṣùgbọ́n ìgbàlà yóò wà lórí òkè Sioni,
Ilé Jakọbu yóò sì jẹ́ iná
Àwọn ará gúúsù yóò ni òkè Esau,
Àwọn ìgbèkùn Israẹli tí ó wà ní Kenaani
Àwọn tó ń gba ni là yóò sì gòkè Sioni wá