Ìran sí Juda àti Jerusalẹmu èyí tí Isaiah ọmọ Amosi rí ní àsìkò ìjọba Ussiah, Jotamu, Ahasi àti Hesekiah àwọn ọba Juda.
JA
Copywork
Yoruba OYCB Isaiah 1장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Isaiah
Gbọ́ ẹ̀yin ọ̀run! Fi etí sílẹ̀, ìwọ ayé!
Màlúù mọ olówó rẹ̀,
Á à! Orílẹ̀-èdè ẹlẹ́ṣẹ̀,
Èéṣe tí a ó fi tún lù yín mọ́?
Láti àtẹ́lẹsẹ̀ yín dé àtàrí yín
Orílẹ̀-èdè yín dahoro,
Ọmọbìnrin Sioni ni a fi sílẹ̀
Àyàfi bí Olúwa àwọn ọmọ-ogun
Gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa,
“Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹbọ yín
Nígbà tí ẹ wá farahàn níwájú mi,
Ẹ má mú ọrẹ asán wá mọ́!
Ayẹyẹ oṣù tuntun yín àti àjọ̀dún tí a yàn,
Nígbà tí ẹ bá tẹ́ ọwọ́ yín sókè ni àdúrà,
“Wẹ̀ kí ẹ sì jẹ́ kí ara yín mọ́.
kọ́ láti ṣe rere!
“Ẹ wá ní ìsinsin yìí, ẹ jẹ́ kí a jọ ṣàṣàrò,”
Tí ẹ̀yin bá fẹ́, tí ẹ sì gbọ́rọ̀,
Ṣùgbọ́n tí ẹ bá kọ̀ tí ẹ sì ṣọ̀tẹ̀,
Wo bí ìlú òtítọ́ ṣe di àgbèrè!
Fàdákà rẹ ti di ìpẹ́pẹ́,
Ọlọ̀tẹ̀ ni àwọn aláṣẹ yín,
Nítorí náà ni Olúwa, Olúwa àwọn ọmọ-ogun,
Èmi yóò pa ọwọ́ mi dà sí ọ,
Èmi yóò mú àwọn adájọ́ rẹ bọ̀ sí ipò gẹ́gẹ́ bí i ti àtijọ́,
A ó fi ìdájọ́ òtítọ́ ra Sioni padà,
Ṣùgbọ́n àwọn ọlọ̀tẹ̀ àti àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ni a ó parun.
“Ojú yóò tì yín nítorí igi óákù mímọ́
Ẹ ó sì dàbí igi óákù tí ewé rẹ̀ ti rọ,
Alágbára ọkùnrin náà yóò sì dàbí ohun ìdáná,