Ní ọjọ́ ìkẹyìn
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀-èdè yóò wá,
Òun yóò sì ṣe ìdájọ́ láàrín ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn,
Ṣùgbọ́n olúkúlùkù yóò jókòó lábẹ́ àjàrà rẹ̀
Gbogbo àwọn ènìyàn ń rìn,
“Ní ọjọ́ náà,” ni Olúwa wí,
Èmi yóò dá àwọn arọ sí fún èyí tókù,
Ní ti ìwọ, ilé ìṣọ́ agbo àgùntàn,
Kí ni ìwọ ha ń kígbe sókè sí nísinsin yìí?
Máa yí síyìn-ín sọ́hùn-ún nínú ìrora,
Ṣùgbọ́n nísinsin yìí ọ̀pọ̀lọpọ̀ Orílẹ̀-èdè kó ara wọn jọ sí ọ.
Ṣùgbọ́n wọn kò mọ
“Dìde, kí ó sì máa pa ọkà ìwọ ọmọbìnrin Sioni,