성경 읽기

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · 창세기 24장

성경이야기 장면

장면 1 · 아브라함이 종을 보냈어요

“Olúwa, Ọlọ́run ọ̀run tí ó mú mi jáde láti ilẹ̀ baba mi àti ní ilẹ̀ tí a bí mi, tí ó bá mi sọ̀rọ̀ tí ó sì búra fún mi pé, ‘Irú-ọmọ rẹ ni n ó fi ilẹ̀ yìí fún,’ yóò rán angẹli rẹ̀ ṣáájú rẹ, kí ìwọ kí ó lè rí aya fẹ́ wá fún ọmọ mi láti ibẹ̀. 창 24:7

다음

본문 이동

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní · 창세기 24장

구약

검색

본문 검색

원어 검색 Strong · lemma · 뜻

버전 범위

본문 범위

설정

보기 옵션

사이트 언어

메뉴, 버튼, 안내문 같은 사이트 UI 문구가 선택한 언어로 표시됩니다.

화면 테마

사이트 디자인

사이트 전체의 레이아웃과 분위기를 바꿉니다. 읽기 화면 디자인은 본문 내부 스타일만 바꿉니다.

읽기 화면 디자인

상세 설정

현재 scripture.how 기본 색감입니다.

선택한 스타일은 이 브라우저에 저장됩니다. 로그인하면 서버에 저장할 수 있습니다.

상단 배경

성경 장면은 이 장에 생성된 hero 이미지를 사용합니다. 아직 이미지가 없으면 기본 배경으로 표시됩니다.

Hero 전환

구절 버튼 표시

선택 시 표시는 PC에서는 구절에 마우스를 올릴 때, 모바일에서는 구절을 선택할 때 자료/멀티/댓글 버튼을 보여줍니다.

글자 크기

글꼴

원어 보기

오른쪽 버튼은 정렬된 단어를 카드(원어사전)로 표시하고, 구절 아래는 모든 원어 토큰을 인라인 표시합니다.

원어 검색 열기

원어 검색

이 원어가 등장하는 모든 구절

불러오는 중...

불러오는 중...

구절 자료

원어, 관주, 주석서, 성경노트, 댓글을 한 곳에서 봅니다.

원어 버튼을 눌러 불러옵니다.

단어를 선택하세요.

멀티성경

현재 절을 멀티성경 설정에 따라 비교합니다.

구절의 멀티성경 버튼을 눌러 불러옵니다.

관주

구절의 관련 성경 본문

불러오는 중...

연관 구절

병행 구절 본문

불러오는 중...

원어사전

구절의 원어 단어

불러오는 중...

단어를 선택하세요.

이미지

성경노트 안내

현재 성경노트 작성자가 함께 읽도록 정리한 색상 의미, 칼럼, 개념사전, 서식 용어를 확인할 수 있습니다.

역본 소개

창세기 읽기 통계

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

이 책 (창세기)

전체 장수
50장
전체 절수
1,533절
현재 장
24 / 50장
이 장 절수
67절
장 진행율48%
절 진행율 (이 장까지)43%

성경 전체 (창세기부터)

현재 장
24 / 1,189장
전체 절수
31,087절
전체 장 진행율2%
전체 절 진행율 (이 장까지)2.1%

성경노트 안내

선택된 성경노트의 필독 정보입니다.

하나님/선

하나님으로부터 오는 진리와 생명의 방향성을 의미합니다. 성경에서 하나님, 말씀, 진리, 생명, 빛, 지혜, 하나님 나라 등은 서로 연결된 본질과 방향성을 나타내는 표현들로 설명됩니다. 성경은 이러한 요소들을 단순히 분리된 개념으로만 설명하지 않고, 서로 연결된 하나의 흐름과 방향성으로 표현합니다. 예를 들어: 진리는 생명과 연결되며 빛은 하나님께 속한 길로 표현되고 말씀에 순종하는 것은 하나님 나라에 속한 삶으로 설명됩니다. 따라서 이 색상은 하나님께 속한 진리와 생명의 방향성과 질서를 나타내는 표현들을 포함합니다.

사탄/악

하나님을 대적하는 거짓과 사망의 방향성을 의미합니다. 성경은 사탄, 거짓, 미혹, 어둠, 사망, 불법, 세상 권세 등을 단순히 분리된 개념으로만 설명하지 않고, 서로 연결된 하나의 방향성과 본질로 묘사합니다. 인간은 이를 존재, 거짓된 가르침, 속성, 결과, 지배 체계 등으로 구분하여 인식하지만, 성경은 이러한 요소들을 서로 연결된 의미로 표현합니다. 예를 들어: 거짓은 사탄에게 속한 것으로 표현되며 어둠은 사망과 연결되고 불법은 하나님을 대적하는 길로 설명되며 세상 권세는 미혹과 멸망의 체계로 묘사됩니다. 따라서 이 색상은 하나님을 거스르는 방향성과 질서를 따르는 표현들을 포함합니다.

선을 따르는 사람

본문의 인물이나 공동체를 선을 따르는 사람의 관점에서 해석할 때 사용합니다. 이 색상은 인물 전체에 대한 최종 판정이 아니라, 해당 구절에서 드러나는 방향성이 하나님께 속한 진리, 생명, 빛, 순종의 흐름으로 읽히는 경우를 표시합니다. 같은 인물이라도 다른 문맥에서는 연약함이나 세상성을 드러낼 수 있으므로, 파란색은 영구 신분표가 아니라 본문 단위의 해석 관점입니다. 특히 어떤 구절은 파란색 관점과 녹색 관점이 모두 가능할 수 있으며, 그런 경우에는 청녹색의 양면 관점으로 표시할 수 있습니다.

양면 관점

같은 구절이나 표현을 파란색 관점과 녹색 관점 모두로 해석할 수 있을 때 사용합니다. 이는 의미 자체가 불명확하다는 뜻이 아니라, 본문을 바라보는 관점에 따라 선을 따르는 사람의 연약함으로도, 세상성이나 육신을 따르는 모습으로도 읽힐 수 있음을 나타냅니다. 따라서 청녹색은 별도의 사람 분류나 최종 판정이 아닙니다. 해석자가 실제로 파란색으로 표시할지 녹색으로 표시할지 고민하게 되는 지점, 두 관점이 병존하는 지점을 표시합니다. 예를 들어 믿음의 방향은 선을 향하지만 본문에서는 육신적 연약함이 두드러지는 경우, 또는 한 표현이 선한 양심의 흔들림으로도 세상성의 작용으로도 읽히는 경우에 사용할 수 있습니다.

세상을 따르는 사람

본문의 인물이나 공동체를 세상, 육신, 불순종의 방향을 따르는 관점에서 해석할 때 사용합니다. 이 색상은 인물 전체를 단정하기 위한 표시가 아니라, 해당 구절에서 드러나는 방향성이 거짓, 어둠, 욕망, 불법, 세상 권세의 흐름으로 읽히는 경우를 표시합니다. 같은 인물이나 같은 표현이라도 문맥에 따라 선을 따르는 사람의 연약함으로 읽힐 수도 있고, 세상성을 따르는 모습으로 읽힐 수도 있습니다. 그런 경우에는 녹색으로 확정하기보다 청녹색의 양면 관점으로 표시할 수 있습니다. 따라서 녹색은 파란색의 반대편 관점을 나타내지만, 모든 연약함을 곧바로 악으로 단정하는 색상은 아닙니다.

강조

본문 흐름에서 특별히 강조할 표현을 표시합니다.

중립

선과 악의 축과 직접 관련 없는 중립적 의미를 나타냅니다. 성경에는 선과 악의 방향성을 직접 나타내기보다, 단순한 배경 정보나 역사적 사실, 일반적인 표현 등으로 사용되는 요소들도 존재합니다. 인간은 이를 지명, 시간, 역사적 사건, 일반 명사, 단순 상황 설명 등으로 구분하여 인식하며, 이러한 표현들은 문맥 설명을 위한 역할로 사용됩니다. 또한 문맥상 선과 악의 의미를 직접 부여하지 않는 경우에는, 특정 인물이나 민족을 설명하는 표현도 중립적으로 사용될 수 있습니다. 예를 들어: 특정 지역이나 시대를 설명하는 표현이 사용되기도 하며 선과 악의 의미를 직접 포함하지 않는 일반적인 사물이나 상황이 묘사되기도 하고 단순한 배경 정보나 역사적 흐름을 설명하는 표현으로 사용되기도 합니다. 또한 문맥에 따라 "이방인", "유대인", "로마인" 등의 표현 역시 선악의 의미를 직접 나타내지 않는 경우에는 중립적으로 사용될 수 있습니다. 따라서 이 색상은 선과 악의 방향성을 직접 나타내지 않는 중립적 표현들을 포함합니다.

A Servant Seeks a Bride for Isaac

1
Abrahamu sì ti di arúgbó ní àkókò yìí, Olúwa sì ti bùkún fún un ni gbogbo ọ̀nà, 카드
원어 9개 불러오는 중...
2
Abrahamu wí fún olórí àwọn ìránṣẹ́ ilẹ̀ rẹ̀, tí ó jẹ́ alábojútó ohun gbogbo tí ó ní pé, “Fi ọwọ́ rẹ sí abẹ́ itan mi. 카드
원어 15개 불러오는 중...
3
Èmi yóò mú ọ búra lórúkọ Olúwa Ọlọ́run ọ̀run àti ayé, pé, ìwọ kì yóò fẹ́ aya fún ọmọ mi nínú àwọn ọmọbìnrin ará Kenaani, láàrín àwọn ẹni tí èmi ń gbé. 카드
원어 17개 불러오는 중...
4
Ṣùgbọ́n, ìwọ yóò lọ sí orílẹ̀-èdè mi, láàrín àwọn ará mi láti fẹ́ aya fún Isaaki, ọmọ mi.” 카드
원어 10개 불러오는 중...
5
Ìránṣẹ́ náà bi í wí pé, “Ǹjẹ́ bí ọmọbìnrin náà bá kọ̀ láti bá mi wá sí ilẹ̀ yìí ń kọ́? Ǹjẹ́ mo lè mú ọmọ rẹ padà lọ sí orílẹ̀-èdè níbi tí ìwọ ti wá?” 카드
원어 21개 불러오는 중...
6
Abrahamu sì wí fún un pé, “Rí i dájú pé ìwọ kò mú ọmọ mi padà lọ sí ibẹ̀.” 카드
원어 10개 불러오는 중...
7
“Olúwa, Ọlọ́run ọ̀run tí ó mú mi jáde láti ilẹ̀ baba mi àti ní ilẹ̀ tí a bí mi, tí ó bá mi sọ̀rọ̀ tí ó sì búra fún mi pé, ‘Irú-ọmọ rẹ ni n ó fi ilẹ̀ yìí fún,’ yóò rán angẹli rẹ̀ ṣáájú rẹ, kí ìwọ kí ó lè rí aya fẹ́ wá fún ọmọ mi láti ibẹ̀. 카드
원어 29개 불러오는 중...
8
Bí obìnrin náà kò bá fẹ́ tẹ̀lé ọ wá, nígbà náà ni a tú ọ sílẹ̀ kúrò nínú ìbúra yìí, ṣùgbọ́n pàtàkì ni pé ìwọ kò gbọdọ̀ mú ọmọ mi padà lọ sí ibẹ̀.” 카드
원어 15개 불러오는 중...
9
Ìránṣẹ́ náà sì fi ọwọ́ rẹ̀ sí abẹ́ itan Abrahamu olúwa rẹ̀, ó sì búra fún nítorí ọ̀rọ̀ náà. 카드
원어 13개 불러오는 중...
10
Ìránṣẹ́ náà sì mú ìbákasẹ mẹ́wàá, pẹ̀lú onírúurú ohun dáradára láti ọ̀dọ̀ olúwa rẹ̀, ó sì dìde ó sì lọ sí Aramu-Naharaimu, sí ìlú Nahori, 카드
원어 19개 불러오는 중...
11
ó sì mú àwọn ìbákasẹ náà kúnlẹ̀ nítòsí kànga lẹ́yìn ìlú, ó ti ń di ọwọ́ ìrọ̀lẹ́ ní àkókò tí àwọn obìnrin máa ń lọ pọn omi. 카드
원어 12개 불러오는 중...
12
Ó sì gbàdúrà wí pé, “Olúwa, Ọlọ́run Abrahamu olúwa à mi; jẹ́ kí n ṣe àṣeyọrí lónìí, sì fi àánú hàn fún Abrahamu olúwa mi. 카드
원어 14개 불러오는 중...
13
Kíyèsi i, mo dúró ní ẹ̀bá kànga omi yìí, àwọn ọmọbìnrin ìlú yìí sì ń jáde wá pọn omi. 카드
원어 12개 불러오는 중...
14
Jẹ́ kí ó ṣe pé nígbà tí mo bá wí fún ọ̀kan nínú àwọn ọmọbìnrin pe, ‘Jọ̀wọ́ sọ ládugbó rẹ kalẹ̀, kí n le mu omi,’ tí ó bá sì wí pé, ‘Mu ún, èmi ó sì fún àwọn ìbákasẹ rẹ náà mu pẹ̀lú,’ jẹ́ kí ó ṣe èyí tí o yàn fún ìránṣẹ́ rẹ Isaaki. Nípa èyí ni n ó fi mọ̀ pé o ti fi àánú hàn fún olúwa mi.” 카드
원어 25개 불러오는 중...
15
Kí o tó di pé, ó parí àdúrà, Rebeka dé pẹ̀lú ìkòkò omi rẹ̀ ní èjìká rẹ̀. Ọmọ Betueli ni. Betueli yìí ni Milka bí fún Nahori arákùnrin Abrahamu. 카드
원어 20개 불러오는 중...
16
Ọmọbìnrin náà rẹwà, wúńdíá ni, kò sì tí ì mọ ọkùnrin, ó lọ sí ibi ìsun omi náà, ó sì pọn omi sínú ìkòkò omi, ó sì gbé e, ó ń gòkè bọ̀ kúrò níbi omi. 카드
원어 13개 불러오는 중...
17
Ìránṣẹ́ náà súré lọ pàdé rẹ̀, ó sì wí fun un pé, “Jọ̀wọ́ fún mi ni omi díẹ̀ nínú ìkòkò omi rẹ.” 카드
원어 9개 불러오는 중...
18
Òun náà dáhùn pé, “Mu, olúwa mi,” ó sì yára sọ ìkòkò omi náà ka ọwọ́ rẹ̀, ó sì fún un mu. 카드
원어 9개 불러오는 중...
19
Lẹ́yìn tí ó ti fún un ni omi mu tán, ó wí pé, “Èmi ó bu omi fún àwọn ìbákasẹ rẹ pẹ̀lú títí wọn yóò fi mu àmutẹ́rùn.” 카드
원어 10개 불러오는 중...
20
Ó sì yára da omi inú ìkòkò omi rẹ̀ sínú ìbùmu, ó sáré padà lọ sí ibi omi láti pọn sí i wá fún àwọn ìbákasẹ, títí tí ó fi pọn fún gbogbo wọn. 카드
원어 13개 불러오는 중...
21
Láìsọ ọ̀rọ̀ kan, ìránṣẹ́ yìí ń wo ọmọbìnrin náà fínní fínní láti mọ̀ bóyá Olúwa ti ṣe ìrìnàjò òun ní rere tàbí bẹ́ẹ̀ kọ́. 카드
원어 10개 불러오는 중...
22
Lẹ́yìn tí àwọn ìbákasẹ náà ti mu omi tán, ni ọkùnrin náà mú òrùka wúrà ààbọ̀ ìwọ̀n ṣékélì àti júfù méjì fún ọwọ́ rẹ̀, tí ìwọ̀n ṣékélì wúrà mẹ́wàá. 카드
원어 18개 불러오는 중...
23
Lẹ́yìn náà, ó béèrè pé, “Ọmọ ta ni ìwọ í ṣe? Jọ̀wọ́ wí fún mi, ǹjẹ́ ààyè wà ní ilé baba rẹ láti wọ̀ sí ní alẹ́ yìí?” 카드
원어 13개 불러오는 중...
24
Ó dáhùn pé, “Betueli ọmọ tí Milka bí fún Nahori ni baba mi.” 카드
원어 10개 불러오는 중...
25
Ó sì fi kún un pé, “Àwa ní koríko àti ṣakaṣaka tó pẹ̀lú, àti ààyè láti wọ̀ sí.” 카드
원어 11개 불러오는 중...
26
Nígbà náà ni ọkùnrin náà tẹríba, ó sì sin Olúwa, 카드
원어 4개 불러오는 중...
27
wí pe, “Olùbùkún ni fún Olúwa, Ọlọ́run Abrahamu olúwa mi ti kò jẹ́ kí àánú àti òtítọ́ rẹ̀ kí ó yẹ̀ lọ́dọ̀ olúwa mi. Ní ti èmi Olúwa ti darí ìrìnàjò mi sí ilé ìbátan olúwa mi.” 카드
원어 20개 불러오는 중...

Rebekah Is Brought Back

28
Ọmọbìnrin náà sì sáré, ó sì lọ sọ ohun gbogbo wọ̀nyí fún àwọn ará ilé ìyá rẹ̀. 카드
원어 7개 불러오는 중...
29
Rebeka ní arákùnrin tí ń jẹ́ Labani; Labani sì sáré lọ bá ọkùnrin náà ní etí odò. 카드
원어 11개 불러오는 중...
30
Bí ó sì ti rí òrùka imú àti ẹ̀gbà ní ọwọ́ arábìnrin rẹ̀ tí ó sì tún gbọ́ ohun tí Rebeka sọ pé ọkùnrin náà sọ fún òun, ó jáde lọ bá ọkùnrin náà, ó sì bá a, ó dúró ti ìbákasẹ wọ̀n-ọn-nì ní ẹ̀bá ìsun omi. 카드
원어 28개 불러오는 중...
31
Ó wí fún ọkùnrin náà pé, “Wá, ìwọ ẹni ìbùkún Olúwa, èéṣe tí o dúró sí ìta níhìn-ín? Mo ti pèsè ààyè sílẹ̀ fún ọ àti ààyè fún àwọn ìbákasẹ rẹ.” 카드
원어 12개 불러오는 중...
32
Ọkùnrin náà sì bá Labani lọ ilé, ó sì tú ẹrù orí ìbákasẹ rẹ̀ sílẹ̀, ó sì fún wọn ni koríko àti oúnjẹ. Ó sì bu omi fún ọkùnrin náà àti àwọn arákùnrin rẹ̀ láti wẹ ẹsẹ̀ wọn. 카드
원어 16개 불러오는 중...
33
Wọ́n sì gbé oúnjẹ síwájú rẹ̀, ṣùgbọ́n, ó wí pé, “Èmi kò ní jẹun àyàfi bí mo bá sọ ohun tí mo ní í sọ.” 카드
원어 13개 불러오는 중...
34
Nítorí náà, ó wí pé, “Ìránṣẹ́ Abrahamu ni èmi. 카드
원어 4개 불러오는 중...
35
Olúwa sì ti bùkún olúwa mi gidigidi. Ó sì ti di ọlọ́rọ̀, Ó sì ti fún un ní àgùntàn, màlúù, àti fàdákà àti wúrà, ìránṣẹ́kùnrin àti ìránṣẹ́bìnrin àti ìbákasẹ àti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́. 카드
원어 16개 불러오는 중...
36
Sara aya olúwa mi sì ti bí ọmọkùnrin kan fún un, ní ìgbà ogbó rẹ̀, olúwa mi sì ti fún ọmọ náà ní ohun gbogbo tí ó ní. 카드
원어 14개 불러오는 중...
37
Olúwa mi sì ti mú mi búra wí pé, ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ fẹ́ aya fún ọmọ mi, láàrín àwọn ọmọbìnrin Kenaani, ní ilẹ̀ ibi tí èmi ń gbé, 카드
원어 13개 불러오는 중...
38
ṣùgbọ́n lọ sí ìdílé baba mi láàrín àwọn ìbátan mi kí o sì fẹ́ aya fún ọmọ mi.’ 카드
원어 11개 불러오는 중...
39
“Mo sì bí olúwa mi léèrè pé, ‘Ǹjẹ́ bí ọmọbìnrin náà kò bá fẹ́ bá mi wá ń kọ́?’ 카드
원어 8개 불러오는 중...
40
“Ó sì dáhùn wí pé, ‘Olúwa, níwájú ẹni tí èmi ń rìn yóò rán Angẹli rẹ̀ ṣáájú rẹ yóò sì jẹ́ kí o ṣe àṣeyọrí ní ìrìnàjò rẹ, kí ìwọ kí ó ba le fẹ́ aya fún ọmọ mi, láàrín àwọn ìbátan mi, àti láàrín àwọn ìdílé baba mi. 카드
원어 17개 불러오는 중...
41
Nígbà tí ìwọ bá lọ sí ọ̀dọ̀ ìdílé baba mi (gẹ́gẹ́ bí mo tí wí), nígbà náà ni ìwọ tó bọ́ nínú ìbúra yìí.’ 카드
원어 14개 불러오는 중...
42
“Nígbà tí mo dé ibi ìsun omi lónìí, mo wí pé, ‘Olúwa Ọlọ́run Abrahamu olúwa mi, bí ìwọ bá fẹ́, jọ̀wọ́ jẹ́ kí n ṣe àṣeyọrí lórí ohun tí mo bá wá yìí. 카드
원어 18개 불러오는 중...
43
Wò ó, mo dúró ní ẹ̀bá ìsun omi yìí, kí ó ṣe pé, nígbà tí wúńdíá kan bá jáde wá pọn omi, tí èmi sì wí fún un pé, “Jọ̀wọ́ fún mi ní ìwọ̀nba omi díẹ̀ mu nínú ládugbó rẹ,” 카드
원어 17개 불러오는 중...
44
tí ó bá sì wí fún mi pé, “Mu ún, èmi yóò sì tún pọn omi fún àwọn ìbákasẹ rẹ pẹ̀lú,” jẹ́ kí ẹni náà jẹ́ ẹni tí Olúwa yàn fún ọmọ Abrahamu, olúwa mi.’ 카드
원어 15개 불러오는 중...
45
“Kí n sì tó gbàdúrà tán nínú ọkàn mi, Rebeka jáde wá pẹ̀lú ìkòkò omi rẹ̀ ní èjìká rẹ̀, ó sì lọ sí ibi ìsun omi ó sì pọn omi. Mo sì wí fun un pé, ‘Jọ̀wọ́ fún mi ni omi mu.’ 카드
원어 19개 불러오는 중...
46
“Kíákíá ni ó sọ ìkòkò rẹ̀ kalẹ̀ láti èjìká rẹ̀, ó sì wí fún mi pé, ‘Mu ún, èmi yóò sì tún fún àwọn ìbákasẹ rẹ mu pẹ̀lú.’ Mo sì mu, ó sì tún fún àwọn ìbákasẹ mi mu pẹ̀lú. 카드
원어 13개 불러오는 중...
47
“Mo béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé, ‘Ọmọ ta ní ìwọ í ṣe?’ 카드
원어 22개 불러오는 중...
48
Èmi sì tẹríba, mo sì wólẹ̀ fún Olúwa, mó sì fi ìbùkún fún Ọlọ́run Abrahamu olúwa mi, ẹni tí ó mú mi tọ ọ̀nà títọ́ láti rí ọmọ ọmọ arákùnrin olúwa mi mú wá fún ọmọ rẹ̀. 카드
원어 19개 불러오는 중...
49
Ǹjẹ́ nísinsin yìí bí ẹ̀yin yóò bá fi inú rere àti òtítọ́ bá olúwa mi lò, ẹ sọ fún mi, bí bẹ́ẹ̀ sì kọ́, ẹ sọ fún mi, kí ń le è mọ ọ̀nà tí èmi yóò yà sí.” 카드
원어 20개 불러오는 중...
50
Labani àti Betueli sì dáhùn pé, “Lọ́dọ̀ Olúwa ni èyí ti wá, nítorí náà àwa kò le sọ rere tàbí búburú fún ọ. 카드
원어 14개 불러오는 중...
51
Rebeka nìyí, mú un kí ó máa lọ, kí ó sì di aya ọmọ olúwa à rẹ, bí Olúwa ti fẹ́.” 카드
원어 12개 불러오는 중...
52
Nígbà tí ọmọ ọ̀dọ̀ Abrahamu gbọ́ ohun tí wọ́n wí, ó wólẹ̀ níwájú Olúwa. 카드
원어 10개 불러오는 중...
53
Nígbà náà ni ó kó ohun èlò wúrà àti fàdákà jáde àti aṣọ, ó sì fi wọ́n fún Rebeka, ó fún arákùnrin Rebeka àti ìyá rẹ̀ ní ẹ̀bùn olówó iyebíye pẹ̀lú. 카드
원어 13개 불러오는 중...
54
Lẹ́yìn náà ni òun àti àwọn ọkùnrin tí ó bá a wá tó jẹ, tí wọ́n sì mu, tí wọn sì sùn níbẹ̀ ní òru ọjọ́ náà. 카드
원어 12개 불러오는 중...
55
Ṣùgbọ́n arákùnrin Rebeka àti ìyá rẹ̀ fèsì pé, “A fẹ́ kí Rebeka wà pẹ̀lú wa fún nǹkan bí ọjọ́ mẹ́wàá sí i, lẹ́yìn èyí, ìwọ le máa mu lọ.” 카드
원어 11개 불러오는 중...
56
Ṣùgbọ́n ó wí fún wọn pé, “Ẹ má ṣe dá mi dúró, Olúwa sá à ti ṣe ọ̀nà mi ní rere. Ẹ rán mi lọ, kí èmi kí ó le è tọ olúwa à mi lọ.” 카드
원어 11개 불러오는 중...
57
Nígbà náà ni wọ́n sọ pé, “Jẹ́ kí a pe ọmọ náà gan an kí a sì bi í.” 카드
원어 6개 불러오는 중...
58
Wọ́n sì pe Rebeka wọ́n sì bi í, wí pé, “Ṣe ìwọ yóò bá ọkùnrin yìí lọ.” 카드
원어 10개 불러오는 중...
59
Wọ́n sì gbà kí Rebeka àti olùtọ́jú rẹ̀, pẹ̀lú ìránṣẹ́ Abrahamu àti àwọn ọkùnrin tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ máa lọ. 카드
원어 11개 불러오는 중...
60
Wọ́n sì súre fún Rebeka, wọn sì wí fun un pé, 카드
원어 15개 불러오는 중...
61
Nígbà náà ni Rebeka àti àwọn ìránṣẹ́bìnrin rẹ̀ múra, wọn sì gun àwọn ìbákasẹ, wọ́n sì bá ọkùnrin náà padà lọ. Ìránṣẹ́ náà sì mú Rebeka, ó sì bá tirẹ̀ lọ. 카드
원어 14개 불러오는 중...
62
Isaaki sì ń ti ọ̀nà kànga Lahai-Roi bọ, nítorí ìhà gúúsù ni ó ń gbé. 카드
원어 10개 불러오는 중...
63
Isaaki sì jáde lọ sí oko ni ìrọ̀lẹ́ láti ṣe àṣàrò, bí ó sì ti gbé ojú sókè, ó rí àwọn ìbákasẹ tí ń bọ̀ wá. 카드
원어 12개 불러오는 중...
64
Rebeka pẹ̀lú sì gbójú sókè, ó sì rí Isaaki. Ó sọ̀kalẹ̀ lórí ìbákasẹ, 카드
원어 10개 불러오는 중...
65
ó sì béèrè lọ́wọ́ ìránṣẹ́ náà wí pé, “Ta ni ọkùnrin tí ń bọ̀ wá pàdé wa láti inú oko?” 카드
원어 16개 불러오는 중...
66
Nígbà náà ni ìránṣẹ́ náà ròyìn fún Isaaki ohun gbogbo tí ó ti ṣe. 카드
원어 8개 불러오는 중...
67
Nígbà náà ni Isaaki mú Rebeka wọ inú àgọ́ ìyá rẹ̀, Sara, ó sì di aya rẹ̀, ó sì fẹ́ràn rẹ̀; ó sì jẹ́ ìtùnú fún Isaaki lẹ́yìn ikú ìyá rẹ̀. 카드
원어 16개 불러오는 중...
주석서 창세기 24장
Matthew Henry's Complete Commentary · Matthew Henry (1714) 퍼블릭 도메인 (PD) 출처

장별/책 단위 주석

책 개요, 장 서론, 여러 장 범위처럼 특정 절이 아닌 단위에 연결된 주석입니다.

장 서론

혼인과 장례는 가정의 변화이며, 마을 사람들 가운데 흔히 오가는 소...

절별/절범위 주석

현재 장의 특정 절이나 절 범위에 직접 연결된 주석입니다.

1-9 Abraham's Charges to His Servant (1857 BC)

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

10-28 Journey of Abraham's Servant (1857 BC)

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

29-53 Abraham's Servant Entertained by Laban; Errand of Abraham's Servant (1857 BC)

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

54-61 Rebekah's Departure (1857 BC)

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

62-67 Isaac's Marriage (1857 BC)

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

Jamieson-Fausset-Brown Commentary Critical and Explanatory on the Whole Bible · Robert Jamieson, A. R. Fausset, David Brown (1871) 퍼블릭 도메인 (PD) 출처

절별/절범위 주석

현재 장의 특정 절이나 절 범위에 직접 연결된 주석입니다.

1 Ge 24:1-9.

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

2 2. 자기 집 모든 소유를 맡은 늙은 종에게 이르되

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

3 3. 너는 . . . 아내를 택하지 말고

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

10 Ge 24:10-67.

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

12 12. 그가 이르되, 우리 주인 아브라함의 하나님 여호와여

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

15 15-21. 말을 마치기도 전에 . . . 보라, 리브가가 나왔더라

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

22 22. 그 사람이 금고리 하나를 취하고

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

23 23-27. 이르되, 네가 누구의 딸이냐?

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

28 28. 소녀가 달려가서 이 일을 어머니 집에 알렸더니

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

29 29-31. 리브가에게 오라비가 있었으니 . . . 라반이 달려나가

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

32 32-49. 그 사람이 집으로 들어가매

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

50 50. 라반과 브두엘이 대답하여

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

53 53. 그 종이 은금 패물들을 꺼내어

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

64 64. 그가 낙타에서 내려

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

65 65. 너울을 가지고 자기 몸을 가리더라

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

67 67. 이삭이 리브가를 인도하여 자기 어머니 . . . 장막으로 들이고

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

Adam Clarke's Commentary and Critical Notes on the Bible · Adam Clarke (1831) 퍼블릭 도메인 (PD) 출처

장별/책 단위 주석

책 개요, 장 서론, 여러 장 범위처럼 특정 절이 아닌 단위에 연결된 주석입니다.

장 서론

Introduction

절별/절범위 주석

현재 장의 특정 절이나 절 범위에 직접 연결된 주석입니다.

1 Verse 1

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

2 Verse 2

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

3 Verse 3

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

4 Verse 4

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

5 Verse 5

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

7 Verse 7

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

9 Verse 9

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

10 Verse 10

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

11 Verse 11

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

12 Verse 12

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

15 Verse 15

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

19 Verse 19

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

21 Verse 21

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

22 Verse 22

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

26 Verse 26

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

27 Verse 27

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

28 Verse 28

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

31 Verse 31

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

32 Verse 32

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

33 Verse 33

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

36 Verse 36

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

42 Verse 42

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

43 Verse 43

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

45 Verse 45

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

49 Verse 49

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

50 Verse 50

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

53 Verse 53

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

54 Verse 54

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

55 Verse 55

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

58 Verse 58

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

59 Verse 59

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

60 Verse 60

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

62 Verse 62

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

63 Verse 63

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

65 Verse 65

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

67 Verse 67

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

Barnes' Notes on the Bible · Albert Barnes (1870) Public Domain 출처

장별/책 단위 주석

책 개요, 장 서론, 여러 장 범위처럼 특정 절이 아닌 단위에 연결된 주석입니다.

장 서론

Marriage Of Isaac

절별/절범위 주석

현재 장의 특정 절이나 절 범위에 직접 연결된 주석입니다.

이 소스에는 현재 장에 직접 연결된 절별 주석이 없습니다.

John Gill's Exposition of the Bible · John Gill (1763) 퍼블릭 도메인 (PD) 출처

장별/책 단위 주석

책 개요, 장 서론, 여러 장 범위처럼 특정 절이 아닌 단위에 연결된 주석입니다.

장 서론

Genesis 24 Introduction

절별/절범위 주석

현재 장의 특정 절이나 절 범위에 직접 연결된 주석입니다.

1 Genesis 24:1

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

2 Genesis 24:2

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

3 Genesis 24:3

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

4 Genesis 24:4

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

5 Genesis 24:5

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

6 Genesis 24:6

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

7 Genesis 24:7

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

8 Genesis 24:8

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

9 Genesis 24:9

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

10 Genesis 24:10

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

11 Genesis 24:11

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

12 Genesis 24:12

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

13 Genesis 24:13

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

14 Genesis 24:14

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

15 Genesis 24:15

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

16 Genesis 24:16

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

17 Genesis 24:17

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

18 Genesis 24:18

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

19 Genesis 24:19

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

20 Genesis 24:20

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

21 Genesis 24:21

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

22 Genesis 24:22

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

23 Genesis 24:23

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

24 Genesis 24:24

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

25 Genesis 24:25

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

26 Genesis 24:26

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

27 Genesis 24:27

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

28 Genesis 24:28

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

29 Genesis 24:29

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

30 Genesis 24:30

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

31 Genesis 24:31

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

32 Genesis 24:32

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

33 Genesis 24:33

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

34 Genesis 24:34

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

35 Genesis 24:35

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

36 Genesis 24:36

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

37 Genesis 24:37

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

38 Genesis 24:38

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

39 Genesis 24:39

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

40 Genesis 24:40

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

41 Genesis 24:41

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

42 Genesis 24:42

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

43 Genesis 24:43

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

44 Genesis 24:44

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

45 Genesis 24:45

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

46 Genesis 24:46

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

47 Genesis 24:47

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

48 Genesis 24:48

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

49 Genesis 24:49

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

50 Genesis 24:50

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

51 Genesis 24:51

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

52 Genesis 24:52

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

53 Genesis 24:53

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

54 Genesis 24:54

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

55 Genesis 24:55

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

56 Genesis 24:56

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

57 Genesis 24:57

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

58 Genesis 24:58

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

59 Genesis 24:59

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

60 Genesis 24:60

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

61 Genesis 24:61

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

62 Genesis 24:62

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

63 Genesis 24:63

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

64 Genesis 24:64

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

65 Genesis 24:65

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

66 Genesis 24:66

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

67 Genesis 24:67

주석서 제목을 열면 내용을 불러옵니다.

원문 주석서는 저작권 보호 기간이 만료된 공개 도메인 저작입니다. scripture.how가 제공하는 한글 번역·편집·구조화 콘텐츠에는 별도 이용 조건이 적용됩니다.

주석

선택한 구절의 주석서 내용