Ègbé ni fún àwọn tí ń gbèrò àìṣedéédéé
Copywork input for chapter 2 verse 1
Your input is saved to this browser automatically.
Wọ́n sì ń ṣe ojúkòkòrò oko, wọ́n sì fi agbára wọn gbà wọ́n,
Copywork input for chapter 2 verse 2
Your input is saved to this browser automatically.
Nítorí náà, Olúwa wí pé:
Copywork input for chapter 2 verse 3
Your input is saved to this browser automatically.
Ní ọjọ́ náà ni ẹnìkan yóò pa òwe kan sí yín;
Copywork input for chapter 2 verse 4
Your input is saved to this browser automatically.
Nítorí náà, ìwọ kò ní ní ẹnìkankan tí yóò ta okùn nínú ìjọ Olúwa,
Copywork input for chapter 2 verse 5
Your input is saved to this browser automatically.
“Ẹ má ṣe sọtẹ́lẹ̀,” ni àwọn wòlíì wọn wí.
Copywork input for chapter 2 verse 6
Your input is saved to this browser automatically.
Ṣé kí á sọ ọ́, ìwọ ilé Jakọbu:
Copywork input for chapter 2 verse 7
Your input is saved to this browser automatically.
Láìpẹ́ àwọn ènìyàn mi dìde
Copywork input for chapter 2 verse 8
Your input is saved to this browser automatically.
Ẹ̀yin sì lé obìnrin àwọn ènìyàn mi
Copywork input for chapter 2 verse 9
Your input is saved to this browser automatically.
Ẹ dìde, kí ẹ sì máa lọ!
Copywork input for chapter 2 verse 10
Your input is saved to this browser automatically.
Tí òpùrọ́ àti ẹlẹ́tàn bá wà tí wọ́n sì wí pé,
Copywork input for chapter 2 verse 11
Your input is saved to this browser automatically.
“Èmi yóò kó gbogbo yín jọ, ìwọ Jakọbu;
Copywork input for chapter 2 verse 12
Your input is saved to this browser automatically.
Ẹni tí ó ń fọ ọ̀nà yóò lọ sókè níwájú wọn;
Copywork input for chapter 2 verse 13