Ègbé ni fún mi!
Copywork input for chapter 7 verse 1
Your input is saved to this browser automatically.
Àwọn olódodo sì ti kúrò ní ilẹ̀ náà,
Copywork input for chapter 7 verse 2
Your input is saved to this browser automatically.
Ọwọ́ wọn méjèèjì ti múra tán láti ṣe búburú;
Copywork input for chapter 7 verse 3
Your input is saved to this browser automatically.
Ẹni tí ó sàn jùlọ nínú wọn sì dàbí ẹ̀gún,
Copywork input for chapter 7 verse 4
Your input is saved to this browser automatically.
Ẹ má ṣe gba ọ̀rẹ́ kan gbọ́;
Copywork input for chapter 7 verse 5
Your input is saved to this browser automatically.
Nítorí tí ọmọkùnrin kò bọ̀wọ̀ fún baba rẹ̀,
Copywork input for chapter 7 verse 6
Your input is saved to this browser automatically.
Ṣùgbọ́n ní tèmi, èmi ní ìwòye ní ìrètí sí Olúwa,
Copywork input for chapter 7 verse 7
Your input is saved to this browser automatically.
Má ṣe yọ̀ mí, ìwọ ọ̀tá mi.
Copywork input for chapter 7 verse 8
Your input is saved to this browser automatically.
Nítorí èmi ti dẹ́ṣẹ̀ sí i,
Copywork input for chapter 7 verse 9
Your input is saved to this browser automatically.
Nígbà náà ni ọ̀tá mi yóò rí i
Copywork input for chapter 7 verse 10
Your input is saved to this browser automatically.
Ọjọ́ tí a ó mọ odi rẹ yóò dé,
Copywork input for chapter 7 verse 11
Your input is saved to this browser automatically.
Ní ọjọ́ náà àwọn ènìyàn yóò wá sọ́dọ̀ rẹ
Copywork input for chapter 7 verse 12
Your input is saved to this browser automatically.
Ilẹ̀ náà yóò di ahoro fún àwọn olùgbé inú rẹ̀,
Copywork input for chapter 7 verse 13
Your input is saved to this browser automatically.
Fi ọ̀pá rẹ bọ́ àwọn ènìyàn, agbo ẹran ìní rẹ,
Copywork input for chapter 7 verse 14
Your input is saved to this browser automatically.
“Bí i ọjọ́ tí ó jáde kúrò ní Ejibiti wá,
Copywork input for chapter 7 verse 15
Your input is saved to this browser automatically.
Orílẹ̀-èdè yóò rí i, ojú yóò sì tì wọ́n,
Copywork input for chapter 7 verse 16
Your input is saved to this browser automatically.
Wọn yóò lá erùpẹ̀ bí ejò,
Copywork input for chapter 7 verse 17
Your input is saved to this browser automatically.
Ta ni Ọlọ́run bí rẹ̀,
Copywork input for chapter 7 verse 18
Your input is saved to this browser automatically.
Òun yóò tún padà yọ́nú sí wa;
Copywork input for chapter 7 verse 19
Your input is saved to this browser automatically.
Ìwọ yóò fi òtítọ́ hàn sí Jakọbu
Copywork input for chapter 7 verse 20