Fi etí sí àdúrà mi, Ọlọ́run,
JA
Copywork
Yoruba OYCB Psalms 55장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Psalms
gbọ́ mi kí o sì dá mi lóhùn.
Sí ohùn àwọn ọ̀tá ni,
Ọkàn mi wà nínú ìrora pẹ̀lú;
Ìbẹ̀rù àti ìwárìrì wa sí ara mi;
Èmi sọ pé, “Èmi ìbá ní ìyẹ́ bí àdàbà!
Èmi ìbá sálọ, jìnnà réré,
èmi ìbá yára lọ́ si ibùgbé mi ní ibi ààbò,
Da àwọn ẹni búburú láàmú, Olúwa, da ahọ́n wọn rú,
Ọ̀sán àti òru ni wọ́n fi ń rìn gbogbo odi kiri;
Ìwà búburú ń bẹ ní àárín rẹ̀;
Tí ọ̀tá bá tàbùkù mi,
Ṣùgbọ́n tí ó bá ṣe ìwọ, ọkùnrin bí ẹgbẹ́ mi,
pẹ̀lú ẹni tí èmi ti jẹ ìgbádùn adùn ìdàpọ̀,
Kí ikú kí ó dé bá wọn,
Ṣùgbọ́n èmi pe Ọlọ́run;
Ní alẹ́, ní òwúrọ̀ àti ní ọ̀sán
Ó rà mí padà láìléwu
Ọlọ́run yóò gbọ́, yóò sì pọ́n wọn lójú àní,
Ọ̀rẹ́ mi yìí ti dalẹ̀ èmi ọ̀rẹ́ rẹ̀;
Ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ̀ kúnná ju òrí-àmọ́,
Gbé ẹrù rẹ lọ sí ọ̀dọ̀ Olúwa
Ṣùgbọ́n ìwọ, Ọlọ́run, ni yóò mu àwọn ọ̀tá mi