Ẹ fi ìyìn fún Olúwa.
JA
Copywork
Yoruba OYCB Psalms 147장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Psalms
Olúwa kọ́ Jerusalẹmu;
Ó wo àwọn tí ọkàn wọ́n bàjẹ́ sàn
Ó ka iye àwọn ìràwọ̀
Títóbi ni Olúwa wa ó sì pọ̀ ní agbára
Olúwa wa pẹ̀lú àwọn onírẹ̀lẹ̀
Fi ọpẹ́ kọrin sí Olúwa
Ó fi ìkùùkuu bo àwọ̀ sánmọ̀
Ó pèsè oúnjẹ fún àwọn ẹranko
Òun kò ní inú dídùn nínú agbára ẹṣin,
Olúwa ni ayọ̀ nínú àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀,
Yin Olúwa, ìwọ Jerusalẹmu;
Nítorí tí ó ti mú ọ̀pá ìdábùú ibodè rẹ̀ lágbára,
Òun jẹ́ kí àlàáfíà wà ní àwọn ẹnu ibodè rẹ̀,
Òun sì rán àṣẹ rẹ̀ sí ayé
Ó fi yìnyín fún ni bi irun àgùntàn
Ó rọ òjò yìnyín rẹ̀ bí òkúta wẹ́wẹ́
Ó rán ọ̀rọ̀ rẹ̀ jáde ó sì mú wọn yọ̀
Ó sọ ọ̀rọ̀ rẹ̀ di mí mọ̀ fún Jakọbu
Òun kó tí ṣe irú èyí sí orílẹ̀-èdè kan rí, bí ó ṣe ti ìdájọ́ rẹ̀