Ó sàn kí ènìyàn jẹ́ tálákà tí ìrìn rẹ̀ kò lábùkù
Copywork input for chapter 19 verse 1
Your input is saved to this browser automatically.
Kò dára láti ní ìtara láìní ìmọ̀,
Copywork input for chapter 19 verse 2
Your input is saved to this browser automatically.
Ìwà òmùgọ̀ ènìyàn fúnra rẹ̀ a pa ẹ̀mí rẹ̀ run;
Copywork input for chapter 19 verse 3
Your input is saved to this browser automatically.
Ọrọ̀ máa ń fa ọ̀rẹ́ púpọ̀;
Copywork input for chapter 19 verse 4
Your input is saved to this browser automatically.
Ajẹ́rìí èké kò ní lọ láìjìyà,
Copywork input for chapter 19 verse 5
Your input is saved to this browser automatically.
Ọ̀pọ̀ ń wá ojúrere olórí;
Copywork input for chapter 19 verse 6
Your input is saved to this browser automatically.
Gbogbo ará ilé e tálákà ni ó pa á tì,
Copywork input for chapter 19 verse 7
Your input is saved to this browser automatically.
Ẹni tí ó gba ọgbọ́n fẹ́ràn ọkàn ara rẹ̀;
Copywork input for chapter 19 verse 8
Your input is saved to this browser automatically.
Ajẹ́rìí èké kì yóò lọ láìjìyà
Copywork input for chapter 19 verse 9
Your input is saved to this browser automatically.
Kò yẹ aláìgbọ́n láti máa gbé nínú ọláńlá,
Copywork input for chapter 19 verse 10
Your input is saved to this browser automatically.
Ọgbọ́n ènìyàn a máa fún un ní sùúrù;
Copywork input for chapter 19 verse 11
Your input is saved to this browser automatically.
Ìbínú ọba dàbí kíké e kìnnìún,
Copywork input for chapter 19 verse 12
Your input is saved to this browser automatically.
Aṣiwèrè ọmọ jẹ́ ìparun baba rẹ̀,
Copywork input for chapter 19 verse 13
Your input is saved to this browser automatically.
A máa ń jogún ilé àti ọrọ̀ lọ́dọ̀ òbí,
Copywork input for chapter 19 verse 14
Your input is saved to this browser automatically.
Ọ̀lẹ ṣíṣe máa ń fa oorun sísùn fọnfọn,
Copywork input for chapter 19 verse 15
Your input is saved to this browser automatically.
Ẹnikẹ́ni tí ó gbọ́ ẹ̀kọ́ pa ẹnu rẹ̀ mọ́,
Copywork input for chapter 19 verse 16
Your input is saved to this browser automatically.
Ẹni tí ó ṣàánú tálákà, Olúwa ní ó yá,
Copywork input for chapter 19 verse 17
Your input is saved to this browser automatically.
Bá ọmọ rẹ wí nítorí nínú ìyẹn ni ìrètí wà;
Copywork input for chapter 19 verse 18
Your input is saved to this browser automatically.
Ènìyàn onínú-fùfù gbọdọ̀ gba èrè ìwà rẹ̀;
Copywork input for chapter 19 verse 19
Your input is saved to this browser automatically.
Fetí sí ìmọ̀ràn kí o sì gba ẹ̀kọ́,
Copywork input for chapter 19 verse 20
Your input is saved to this browser automatically.
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ète inú ọkàn ènìyàn,
Copywork input for chapter 19 verse 21
Your input is saved to this browser automatically.
Ohun tí ènìyàn ń fẹ́ ni ìfẹ́ tí kì í yẹ̀;
Copywork input for chapter 19 verse 22
Your input is saved to this browser automatically.
Ìbẹ̀rù Olúwa ń mú ìyè wá;
Copywork input for chapter 19 verse 23
Your input is saved to this browser automatically.
Ọ̀lẹ ki ọwọ́ rẹ̀ bọ inú àwo oúnjẹ;
Copywork input for chapter 19 verse 24
Your input is saved to this browser automatically.
Na ẹlẹ́gàn, òpè yóò sì kọ́gbọ́n;
Copywork input for chapter 19 verse 25
Your input is saved to this browser automatically.
Ẹni tí ó ṣìkà sí baba rẹ̀, tí ó sì lé ìyá rẹ̀ jáde
Copywork input for chapter 19 verse 26
Your input is saved to this browser automatically.
Ọmọ mi, dẹ́kun láti tẹ́tí sí ẹ̀kọ́,
Copywork input for chapter 19 verse 27
Your input is saved to this browser automatically.
Ẹlẹ́rìí búburú fi ìdájọ́ ṣẹ̀sín,
Copywork input for chapter 19 verse 28
Your input is saved to this browser automatically.
A ti pèsè ìjìyà sílẹ̀ fún ẹlẹ́gàn;
Copywork input for chapter 19 verse 29