Má ṣe ṣe ìlara àwọn ènìyàn búburú
Copywork input for chapter 24 verse 1
Your input is saved to this browser automatically.
nítorí ọkàn wọn ń gbèrò ohun búburú,
Copywork input for chapter 24 verse 2
Your input is saved to this browser automatically.
Nípa ọgbọ́n ni ilé di kíkọ́
Copywork input for chapter 24 verse 3
Your input is saved to this browser automatically.
nípa ìmọ̀ ni àwọn yàrá rẹ̀ kún
Copywork input for chapter 24 verse 4
Your input is saved to this browser automatically.
Ọlọ́gbọ́n ènìyàn ní agbára púpọ̀,
Copywork input for chapter 24 verse 5
Your input is saved to this browser automatically.
Láti jagun, ó nílò ìtọ́sọ́nà:
Copywork input for chapter 24 verse 6
Your input is saved to this browser automatically.
Ọgbọ́n ga ju fún aṣiwèrè
Copywork input for chapter 24 verse 7
Your input is saved to this browser automatically.
Ẹni tí ń pète ibi
Copywork input for chapter 24 verse 8
Your input is saved to this browser automatically.
Ète òmùgọ̀ ènìyàn jẹ́ ẹ̀ṣẹ̀,
Copywork input for chapter 24 verse 9
Your input is saved to this browser automatically.
Bí ìwọ bá dákú lásìkò ìdààmú
Copywork input for chapter 24 verse 10
Your input is saved to this browser automatically.
Gba àwọn tí a ń wọ́ lọ sí ibi ikú là;
Copywork input for chapter 24 verse 11
Your input is saved to this browser automatically.
Bí ìwọ bá wí pé, “Ṣùgbọ́n a kò mọ nǹkan kan nípa èyí,”
Copywork input for chapter 24 verse 12
Your input is saved to this browser automatically.
Jẹ oyin, ìwọ ọmọ mi, nítorí tí ó dára,
Copywork input for chapter 24 verse 13
Your input is saved to this browser automatically.
Mọ̀ pẹ̀lú pé ọgbọ́n pẹ̀lú dùn fún ọkàn rẹ
Copywork input for chapter 24 verse 14
Your input is saved to this browser automatically.
Má ṣe ba ní ibùba bí ènìyàn búburú
Copywork input for chapter 24 verse 15
Your input is saved to this browser automatically.
nítorí bí olódodo ènìyàn bá tilẹ̀ ṣubú ní ìgbà méje, yóò tún padà dìde sá á ni,
Copywork input for chapter 24 verse 16
Your input is saved to this browser automatically.
Má ṣe yọ̀ nígbà tí ọ̀tá rẹ bá ṣubú;
Copywork input for chapter 24 verse 17
Your input is saved to this browser automatically.
Àìṣe bẹ́ẹ̀ Olúwa yóò rí i yóò sì bínú
Copywork input for chapter 24 verse 18
Your input is saved to this browser automatically.
Má ṣe fòyà nítorí àwọn ènìyàn ibi
Copywork input for chapter 24 verse 19
Your input is saved to this browser automatically.
nítorí ẹni ibi kò ní ìrètí ọjọ́ iwájú
Copywork input for chapter 24 verse 20
Your input is saved to this browser automatically.
Bẹ̀rù Olúwa àti ọba, ọmọ mi,
Copywork input for chapter 24 verse 21
Your input is saved to this browser automatically.
Nítorí àwọn méjèèjì yóò rán ìparun òjijì sórí wọn,
Copywork input for chapter 24 verse 22
Your input is saved to this browser automatically.
Àwọn wọ̀nyí pẹ̀lú tún jẹ́ ọ̀rọ̀ ọlọ́gbọ́n:
Copywork input for chapter 24 verse 23
Your input is saved to this browser automatically.
Ẹnikẹ́ni tí ó wí fún ẹlẹ́bi pé, “Ìwọ lo jàre,”
Copywork input for chapter 24 verse 24
Your input is saved to this browser automatically.
Ṣùgbọ́n yóò dára fún àwọn tí ń dá ẹlẹ́bi lẹ́bi,
Copywork input for chapter 24 verse 25
Your input is saved to this browser automatically.
Ìdáhùn òtítọ́
Copywork input for chapter 24 verse 26
Your input is saved to this browser automatically.
Parí gbogbo iṣẹ́ ajé rẹ
Copywork input for chapter 24 verse 27
Your input is saved to this browser automatically.
Má ṣe rojọ́ èké mọ́ aládùúgbò rẹ láìnídìí,
Copywork input for chapter 24 verse 28
Your input is saved to this browser automatically.
Má ṣe wí pé, “Èmi yóò ṣe é fún un gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe fún mi;
Copywork input for chapter 24 verse 29
Your input is saved to this browser automatically.
Mo kọjá níbi oko ọ̀lẹ,
Copywork input for chapter 24 verse 30
Your input is saved to this browser automatically.
ẹ̀gún ti hù ní ibi gbogbo,
Copywork input for chapter 24 verse 31
Your input is saved to this browser automatically.
Mo fi ọkàn mi sí nǹkan tí mo kíyèsi
Copywork input for chapter 24 verse 32
Your input is saved to this browser automatically.
oorun díẹ̀, òògbé díẹ̀,
Copywork input for chapter 24 verse 33
Your input is saved to this browser automatically.
òsì yóò sì dé bá ọ bí adigunjalè
Copywork input for chapter 24 verse 34