Ọmọ mi, bí ìwọ bá ṣe onídùúró fún aládùúgbò rẹ,
Copywork input for chapter 6 verse 1
Your input is saved to this browser automatically.
bí a bá ti fi ọ̀rọ̀ tí ó sọ dẹkùn mú ọ,
Copywork input for chapter 6 verse 2
Your input is saved to this browser automatically.
Nígbà náà, ṣe èyí, ìwọ ọmọ mi, láti gba ara rẹ
Copywork input for chapter 6 verse 3
Your input is saved to this browser automatically.
Má ṣe jẹ́ kí oorun kí ó kùn ọ́,
Copywork input for chapter 6 verse 4
Your input is saved to this browser automatically.
Gba ara rẹ sílẹ̀, bí abo èsúró kúrò lọ́wọ́ ọdẹ,
Copywork input for chapter 6 verse 5
Your input is saved to this browser automatically.
Tọ èèrà lọ, ìwọ ọ̀lẹ;
Copywork input for chapter 6 verse 6
Your input is saved to this browser automatically.
Kò ní olùdarí,
Copywork input for chapter 6 verse 7
Your input is saved to this browser automatically.
síbẹ̀, a kó ìpèsè rẹ̀ jọ ní àsìkò òjò
Copywork input for chapter 6 verse 8
Your input is saved to this browser automatically.
Yóò ti pẹ́ tó tí ìwọ yóò dùbúlẹ̀, ìwọ ọ̀lẹ?
Copywork input for chapter 6 verse 9
Your input is saved to this browser automatically.
Oorun díẹ̀, òògbé díẹ̀,
Copywork input for chapter 6 verse 10
Your input is saved to this browser automatically.
Òsì yóò sì wá sórí rẹ bí ìgárá ọlọ́ṣà
Copywork input for chapter 6 verse 11
Your input is saved to this browser automatically.
Ènìyànkénìyàn àti ènìyàn búburú,
Copywork input for chapter 6 verse 12
Your input is saved to this browser automatically.
tí ó ń ṣẹ́jú pàkòpàkò,
Copywork input for chapter 6 verse 13
Your input is saved to this browser automatically.
tí ó ń pète búburú pẹ̀lú ẹ̀tàn nínú ọkàn rẹ̀
Copywork input for chapter 6 verse 14
Your input is saved to this browser automatically.
Nítorí náà ìdààmú yóò dé bá a ní ìṣẹ́jú akàn;
Copywork input for chapter 6 verse 15
Your input is saved to this browser automatically.
Àwọn ohun mẹ́fà wà tí Olúwa kórìíra,
Copywork input for chapter 6 verse 16
Your input is saved to this browser automatically.
Ojú ìgbéraga,
Copywork input for chapter 6 verse 17
Your input is saved to this browser automatically.
ọkàn tí ń pète ohun búburú,
Copywork input for chapter 6 verse 18
Your input is saved to this browser automatically.
ajẹ́rìí èké tí ń tú irọ́ jáde lẹ́nu
Copywork input for chapter 6 verse 19
Your input is saved to this browser automatically.
Ọmọ mi, pa àṣẹ baba rẹ mọ́
Copywork input for chapter 6 verse 20
Your input is saved to this browser automatically.
Jẹ́ kí wọn wà nínú ọkàn rẹ láéláé
Copywork input for chapter 6 verse 21
Your input is saved to this browser automatically.
Nígbà tí ìwọ bá ń rìn, wọn yóò ṣe amọ̀nà rẹ;
Copywork input for chapter 6 verse 22
Your input is saved to this browser automatically.
Nítorí àwọn àṣẹ yìí jẹ́ fìtílà,
Copywork input for chapter 6 verse 23
Your input is saved to this browser automatically.
Yóò pa ọ́ mọ́ kúrò lọ́wọ́ obìnrin búburú,
Copywork input for chapter 6 verse 24
Your input is saved to this browser automatically.
Má ṣe ṣe ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ si nínú ọkàn rẹ nítorí ẹwà rẹ
Copywork input for chapter 6 verse 25
Your input is saved to this browser automatically.
Nítorí pé nípasẹ̀ àgbèrè obìnrin ni ènìyàn fi ń di oníṣù-àkàrà kan,
Copywork input for chapter 6 verse 26
Your input is saved to this browser automatically.
Ǹjẹ́ ọkùnrin ha le è gbé iná lé orí itan
Copywork input for chapter 6 verse 27
Your input is saved to this browser automatically.
Ǹjẹ́ ènìyàn le è máa rìn lórí iná?
Copywork input for chapter 6 verse 28
Your input is saved to this browser automatically.
Bẹ́ẹ̀ ni ẹni tí ń lọ sùn pẹ̀lú aya aláya;
Copywork input for chapter 6 verse 29
Your input is saved to this browser automatically.
Àwọn ènìyàn kì í kẹ́gàn olè tí ó bá jalè
Copywork input for chapter 6 verse 30
Your input is saved to this browser automatically.
Síbẹ̀ bí ọwọ́ bá tẹ̀ ẹ́, ó gbọdọ̀ san ìlọ́po méje
Copywork input for chapter 6 verse 31
Your input is saved to this browser automatically.
Ṣùgbọ́n ẹni tí ń ṣe àgbèrè kò nírònú;
Copywork input for chapter 6 verse 32
Your input is saved to this browser automatically.
Ìfarapa àti ìtìjú ni tirẹ̀,
Copywork input for chapter 6 verse 33
Your input is saved to this browser automatically.
Nítorí owú yóò ru ìbínú ọkọ sókè,
Copywork input for chapter 6 verse 34
Your input is saved to this browser automatically.
Kò nígbà nǹkan kan bí ohun ìtánràn;
Copywork input for chapter 6 verse 35