Ti ènìyàn ni ìgbèrò inú ọkàn
KO
Copywork
Yoruba OYCB 잠언 16장
성경필사는 빠르게 끝내는 입력 훈련이 아니라, 한 절씩 말씀의 문장과 흐름을 다시 붙드는 시간입니다. 입력 내용은 이 브라우저에 임시 저장되며, 로그인하면 계정에도 저장됩니다.
소제목 단위로 진행 · 잠언
Gbogbo ọ̀nà ènìyàn ni ó dàbí i pé ó dára lójú ara rẹ̀
Fi ohun gbogbo tí o bá ṣe lé Olúwa lọ́wọ́,
Olúwa ti ṣe ohun gbogbo láti mú kí ó rí bí ó ṣe fẹ́
Olúwa kórìíra gbogbo ẹni tí ń gbéraga lọ́kàn rẹ̀
Nípasẹ̀ ìfẹ́ àti òtítọ́ a ṣe ètùtù ẹ̀ṣẹ̀
Nígbà tí ọ̀nà ènìyàn bá tẹ́ Olúwa lọ́rùn,
Ó sàn kí ó kéré pẹ̀lú òdodo
Ènìyàn a máa pète ọ̀nà ara rẹ̀ lọ́kàn an rẹ̀
Ètè ọba a máa sọ̀rọ̀ nípa àṣẹ sí i
Òdínwọ̀n àti òsùwọ̀n òtítọ́ wá láti ọ̀dọ̀ Olúwa;
Àwọn ọba kórìíra ìwà àìtọ́
Àwọn ọba ní inú dídùn sí ètè tí ń ṣọ òtítọ́,
Ìránṣẹ́ ikú ni ìbínú ọba jẹ́
Nígbà tí ojú ọba bá túká, ó túmọ̀ sí ìyè;
Ó ti dára tó láti ní ọgbọ́n ju wúrà lọ
Òpópó ọ̀nà àwọn ẹni dídúró ṣinṣin yàgò fún ibi,
Ìgbéraga ní í ṣáájú ìparun,
Ó sàn láti jẹ́ onírẹ̀lẹ̀ ọkàn láàrín àwọn olùpọ́njú
Ẹnikẹ́ni tí ó bá tẹ̀lé ẹ̀kọ́ yóò rí ìre,
Àwọn tí ó gbọ́n nínú ọkàn là ń pè ní olóye
Òye jẹ́ orísun ìyè fún àwọn tí ó ní i,
Ọkàn ọlọ́gbọ́n ènìyàn a máa ṣọ́ ẹnu rẹ̀
Ọ̀rọ̀ ìtura dàbí afárá oyin
Ọ̀nà kan tí ó dàbí i pé ó dára lójú ènìyàn
Ọkàn alágbàṣe ń ṣiṣẹ́ fún ara rẹ̀;
Ènìyàn búburú ń pète
Aláyídáyidà ènìyàn dá ìjà sílẹ̀
Oníjàgídíjàgan ènìyàn tan aládùúgbò rẹ̀
Ẹni tí ń ṣẹ́jú ń pètekéte;
Adé ògo ni ewú orí jẹ́,
Ó sàn láti jẹ́ onísùúrù ju ajagun ènìyàn lọ,
A ṣẹ́ kèké si ìṣẹ́po aṣọ,