Nígbà tí ìwọ bá jókòó láti bá ìjòyè jẹun,
KO
Copywork
Yoruba OYCB 잠언 23장
성경필사는 빠르게 끝내는 입력 훈련이 아니라, 한 절씩 말씀의 문장과 흐름을 다시 붙드는 시간입니다. 입력 내용은 이 브라우저에 임시 저장되며, 로그인하면 계정에도 저장됩니다.
소제목 단위로 진행 · 잠언
Ìwọ a sì fi ọ̀bẹ lé ara rẹ ní ọ̀fun,
Má ṣe fẹ́ oúnjẹ dídùn rẹ̀:
Má ṣe ṣe làálàá láti lọ́rọ̀:
Ìwọ ó ha fi ojú rẹ lépa ohun tí kò sí?
Má ṣe jẹ oúnjẹ ẹni tí ó háwọ́,
Nítorí pé bí ẹni tí ń ṣírò ní ọkàn rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni ó rí:
Òkèlè tí ìwọ jẹ ni ìwọ ó pọ̀ jáde,
Má ṣe sọ̀rọ̀ ní etí aṣiwèrè;
Má ṣe ṣí ààlà àtijọ́ kúrò;
Nítorí pé Olùràpadà wọn lágbára;
Fi àyà sí ẹ̀kọ́,
Má ṣe fa ọwọ́ ìbáwí sẹ́yìn kúrò lára ọmọdé,
Bí ìwọ fi pàṣán nà án,
Ọmọ mi, bí ọkàn rẹ bá gbọ́n,
Inú mi yóò sì dùn nígbà tí ètè rẹ̀ bá ń sọ̀rọ̀ títọ́.
Má ṣe jẹ́ kí àyà rẹ ó ṣe ìlara sí àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀,
Nítorí pé ìgbẹ̀yìn ń bẹ nítòótọ́;
Gbọ́, ìwọ ọmọ mi, kí o sì gbọ́n,
Má ṣe wà nínú àwọn ọ̀mùtí;
nítorí pé ọ̀mùtí àti ọ̀jẹun ni yóò di tálákà;
Fetí sí ti baba rẹ tí ó bí ọ,
Ra òtítọ́, kí o má sì ṣe tà á;
Baba olódodo ni yóò yọ̀ gidigidi:
Jẹ́ kí baba rẹ àti ìyá rẹ ó yọ̀,
Ọmọ mi, fi àyà rẹ fún mi,
Nítorí pé panṣágà obìnrin ọ̀gbun jíjìn ni;
Òun á sì ba ní bùba bí olè,
Ta ni ó ni òsì? Ta ni ó ni ìbànújẹ́?
Àwọn tí ó dúró pẹ́ níbi ọtí wáìnì;
Ìwọ má ṣe wò ọtí wáìnì nígbà tí ó pọ́n,
Níkẹyìn òun á bu ni ṣán bí ejò,
Ojú rẹ yóò wò àwọn àjèjì obìnrin,
Nítòótọ́, ìwọ ó dàbí ẹni tí ó dùbúlẹ̀ ní àárín Òkun,
Ìwọ ó sì wí pé, “Wọ́n lù mí; kò dùn mí;