Ọmọ mi, pa ọ̀rọ̀ mi mọ́,
KO
Copywork
Yoruba OYCB 잠언 7장
성경필사는 빠르게 끝내는 입력 훈련이 아니라, 한 절씩 말씀의 문장과 흐름을 다시 붙드는 시간입니다. 입력 내용은 이 브라우저에 임시 저장되며, 로그인하면 계정에도 저장됩니다.
소제목 단위로 진행 · 잠언
Pa òfin mi mọ́, ìwọ yóò sì yè
Kọ wọ́n sí ọwọ́ òsì rẹ, má ṣe fi jẹun
Wí fún ọgbọ́n pé, “Ìwọ ni arábìnrin mi,”
Wọn yóò pa ó mọ́ kúrò lọ́wọ́ obìnrin alágbèrè,
Ní ojú fèrèsé ilé è mi
Mo rí i láàrín àwọn aláìmọ̀kan
Ó ń lọ ní pópónà ní tòsí i ilé alágbèrè obìnrin náà,
Ní ìrọ̀lẹ́ bí oòrùn ṣe ń wọ̀,
Bẹ́ẹ̀ ni obìnrin kan jáde wá láti pàdé rẹ̀,
(Ó jẹ́ aláriwo àti alágídí,
bí ó ti ń já níhìn-ín ní ó ń já lọ́hùn ún
Ó dìímú, ó sì fẹnukò ó ní ẹnu
“Mo ní ọrẹ àlàáfíà ní ilé;
Nítorí náà ni n o ṣe jáde wá pàdé è rẹ;
Mo ti tẹ́ ibùsùn mi
Mo ti fi nǹkan olóòórùn dídùn sí ibùsùn mi
Wá, jẹ́ kí a lo ìfẹ́ papọ̀ ní kíkún títí di àárọ̀;
Ọkọ ọ̀ mi ò sí nílé;
Ó mú owó púpọ̀ lọ́wọ́
Pẹ̀lú ọ̀rọ̀ dídùn ó sì í lọ́nà;
Òun sì tọ̀ ọ́ lọ lẹsẹ̀ kan náà,
Títí tí ọ̀kọ̀ fi gún un ní ẹ̀dọ̀,
Nítorí náà báyìí ẹ̀yin ọmọ mi, tẹ́tí sí mi
Má ṣe jẹ́ kí ọkàn rẹ kí ó yà sí ọ̀nà rẹ̀,
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni àwọn tí ó ti fà lulẹ̀.
Ilé e rẹ̀ ni ọ̀nà tààrà sí isà òkú,