Ẹni tí ó sì ń ṣorí kunkun lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìbáwí
KO
Copywork
Yoruba OYCB 잠언 29장
성경필사는 빠르게 끝내는 입력 훈련이 아니라, 한 절씩 말씀의 문장과 흐름을 다시 붙드는 시간입니다. 입력 내용은 이 브라우저에 임시 저장되며, 로그인하면 계정에도 저장됩니다.
소제목 단위로 진행 · 잠언
Nígbà tí olódodo bá ń gbilẹ̀, àwọn ènìyàn a yọ̀
Ènìyàn tí ó fẹ́ràn ọgbọ́n mú kí baba rẹ̀ láyọ̀
Nípa ìdájọ́ òdodo ni ọba fi í mú ìlú tòrò nini,
Ẹnikẹ́ni tí ó bá tan aládùúgbò rẹ̀
Ẹ̀ṣẹ̀ ènìyàn ibi ni ó jẹ́ ìdẹ̀kùn rẹ̀
Olódodo ń máa ro ọ̀rọ̀ tálákà,
Àwọn ẹlẹ́yà a máa ru ìlú sókè,
Bí ọlọ́gbọ́n ènìyàn bá lọ sí ilé ẹjọ́ pẹ̀lú aláìgbọ́n
Àwọn tí ó ń tàjẹ̀ sílẹ̀ kò rí ẹni dídúró ṣinṣin
Aláìgbọ́n ènìyàn fi gbogbo ẹnu rẹ̀ bínú
Bí olórí bá fetí sí irọ́,
Tálákà ènìyàn àti aninilára jọ ní àbùdá yìí,
Bí ọba kan bá ń ṣe ìdájọ́ tálákà pẹ̀lú òtítọ́
Ọ̀pá ìbániwí ń fún ni ní ọgbọ́n
Nígbà tí ènìyàn búburú ń gbilẹ̀, bẹ́ẹ̀ náà ni ẹ̀ṣẹ̀ ń gbilẹ̀
Bá ọmọ rẹ wí, yóò sì fún ọ ní àlàáfíà
Níbi tí kò ti sí ìfihàn, àwọn ènìyàn a gbé ìgbé ayé àìbìkítà,
A kò le fi ọ̀rọ̀ lásán kìlọ̀ fún ìránṣẹ́
Ǹjẹ́ ó rí ènìyàn tí ń kánjú sọ̀rọ̀?
Bí ènìyàn kan bá kẹ́ ìránṣẹ́ rẹ̀ lákẹ̀ẹ́jù láti kékeré
Oníbìínú ènìyàn a ru ìjà sókè,
Ìgbéraga ènìyàn a máa sọ ọ́ di ẹni ilẹ̀
Ẹni tí ó ń kó ẹgbẹ́, olè kórìíra ọkàn ara rẹ̀,
Ìbẹ̀rù ènìyàn kan yóò sì di ìdẹ̀kùn
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ń wá ojúrere alákòóso,
Olódodo kórìíra àwọn aláìṣòótọ́: