Àwọn ọ̀rọ̀ Aguri ọmọ Jake, ọ̀rọ̀ ìsọtẹ́lẹ̀ tí ọkùnrin yìí sọ fún Itieli.
KO
Copywork
Yoruba OYCB 잠언 30장
성경필사는 빠르게 끝내는 입력 훈련이 아니라, 한 절씩 말씀의 문장과 흐름을 다시 붙드는 시간입니다. 입력 내용은 이 브라우저에 임시 저장되며, 로그인하면 계정에도 저장됩니다.
소제목 단위로 진행 · 잠언
“Èmi ni aláìmòye ju nínú àwọn ènìyàn;
Èmi kò tilẹ̀ kọ́ ọgbọ́n
Ta ni ó ti gòkè lọ sí ọ̀run tí ó sì padà sọ̀kalẹ̀?
“Gbogbo ọ̀rọ̀ Ọlọ́run jẹ́ aláìlábùkù;
Má ṣe fi kún ọ̀rọ̀ rẹ̀,
“Ohun méjì ni mo ń béèrè lọ́wọ́ rẹ, Olúwa;
Mú èké ṣíṣe àti irọ́ jìnnà sí mi;
Àìṣe bẹ́ẹ̀, mo lè ní àníjù kí n sì gbàgbé rẹ
“Má ṣe ba ìránṣẹ́ lórúkọ jẹ́ lọ́dọ̀ ọ̀gá rẹ̀,
“Àwọn kan wá ṣépè fún àwọn baba wọn
Àwọn tí ó mọ́ ní ojú ara wọn
àwọn ẹni tí ojú wọn gbéga nígbà gbogbo,
Àwọn ẹni tí eyín wọn jẹ́ idà
“Eṣúṣú ni ọmọbìnrin méjì.
Ibojì, inú tí ó yàgàn,
“Ojú tí ń fi baba ṣẹ̀fẹ̀,
“Àwọn nǹkan mẹ́ta wà tí ó jẹ́ ìyàlẹ́nu fún mi,
ipa ẹyẹ idì ní òfúrufú
“Èyí ni ọ̀nà alágbèrè obìnrin
“Lábẹ́ nǹkan mẹ́ta ni ilé ayé ti ń wárìrì
Ìránṣẹ́ tí ó di ọba
obìnrin tí gbogbo ènìyàn kórìíra tí ó sì wá lọ́kọ
“Àwọn ohun mẹ́rin ló kéré láyé
Àwọn èèrà jẹ́ aláìlágbára ẹ̀dá,
Ehoro jẹ́ aláìlágbára ẹ̀dá;
àwọn eṣú kò ní ọba,
Ọmọnílé fi ọwọ́ rẹ̀ dì mú,
“Àwọn ohun mẹ́ta ní ń bẹ tí ń rìn rere,
Kìnnìún, alágbára láàrín ẹranko tí kì í sá fún ohunkóhun
Ẹsin tí a dì lẹ́gbẹ̀ẹ́;
“Bí ìwọ bá ti hùwà aṣiwèrè nípa gbígbé ara rẹ ga,
Nítorí bí fífún omi ọmú tí í mú wàrà wá,