Olúwa kórìíra òsùwọ̀n èké,
KO
Copywork
Yoruba OYCB 잠언 11장
성경필사는 빠르게 끝내는 입력 훈련이 아니라, 한 절씩 말씀의 문장과 흐름을 다시 붙드는 시간입니다. 입력 내용은 이 브라우저에 임시 저장되며, 로그인하면 계정에도 저장됩니다.
소제목 단위로 진행 · 잠언
Nígbà tí ìgbéraga bá dé, nígbà náà ni ìdójútì dé,
Òtítọ́ inú ẹni dídúró ṣinṣin ń ṣe amọ̀nà rẹ̀,
Ọ̀rọ̀ kò níláárí ní ọjọ́ ìbínú,
Òdodo aláìlẹ́gàn ṣe ọ̀nà tààrà fún wọn,
Òdodo ẹni ìdúró ṣinṣin gbà wọ́n là,
Nígbà tí ènìyàn búburú bá kú, ìrètí rẹ̀ a parun;
A gba olódodo kúrò lọ́wọ́ ibi dípò o rẹ̀,
Aláìmọ Ọlọ́run fi ẹnu rẹ̀ ba aládùúgbò rẹ̀ jẹ́,
Nígbà tí olódodo ń gbèrú, ìlú a yọ̀;
Nípasẹ̀ ìbùkún, olódodo a gbé ìlú ga:
Ẹni tí kò gbọ́n fojú kékeré wo aládùúgbò rẹ̀
Olófòófó tú àṣírí ìkọ̀kọ̀
Nítorí àìní ìtọ́sọ́nà orílẹ̀-èdè ṣubú
Ẹni tí ó ṣe onígbọ̀wọ́ fún àlejò yóò rí ìyọnu,
Obìnrin oníwà rere gba ìyìn
Ènìyàn rere ń ṣe ara rẹ̀ lóore
Ènìyàn búburú gba èrè ìtànjẹ
Olódodo tòótọ́ rí ìyè
Olúwa kórìíra àwọn ènìyàn ọlọ́kàn búburú
Mọ èyí dájú pé, ènìyàn búburú kì yóò lọ láìjìyà,
Bí òrùka wúrà ní imú ẹlẹ́dẹ̀
Ìfẹ́ inú olódodo yóò yọrí sí ohun rere
Ènìyàn kan ń fún ni lọ́fẹ̀ẹ́, síbẹ̀ ó ń ní sí i;
Ẹni tí ń ṣoore yóò máa gbèrú sí i;
Àwọn ènìyàn a ṣẹ́ èpè lé ènìyàn tí ń kó oúnjẹ pamọ́
Ẹni tí ń lépa ohun rere yóò rí ohun rere
Ẹnikẹ́ni tí ó bá gbẹ́kẹ̀lé ọrọ̀ rẹ̀ yóò ṣubú;
Ẹni tí ó ń mú ìdààmú dé bá ìdílé rẹ̀ yóò jogún afẹ́fẹ́ lásán
Èso òdodo ni igi ìyè
Bí àwọn olódodo bá gba ìpín wọn lórí ilẹ̀ ayé