Ènìyàn búburú ń sá bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹnìkan kò lé e
KO
Copywork
Yoruba OYCB 잠언 28장
성경필사는 빠르게 끝내는 입력 훈련이 아니라, 한 절씩 말씀의 문장과 흐름을 다시 붙드는 시간입니다. 입력 내용은 이 브라우저에 임시 저장되며, 로그인하면 계정에도 저장됩니다.
소제목 단위로 진행 · 잠언
Nígbà tí orílẹ̀-èdè bá ní orí kunkun, àwọn ọba rẹ̀ a máa pọ̀,
Ọba tí ó ni àwọn tálákà lára
Àwọn tí ó kọ òfin sílẹ̀ a máa gbóríyìn fún ènìyàn búburú
Òye ìdájọ́ òdodo kò yé àwọn ẹni ibi
Ó sàn láti jẹ́ tálákà tí ìrìn rẹ̀ jẹ́ aláìlábùkù
Ẹni tí ó pa òfin mọ́ jẹ́ olóye ọmọ
Ẹni tí ó mú ọrọ̀ rẹ̀ di púpọ̀ nípa èrè àjẹjù
Bí ẹnikẹ́ni bá kọ etí ikún sí òfin,
Ẹni tí ó mú olódodo rìn ọ̀nà búburú
Ọlọ́rọ̀ ènìyàn le è gbọ́n lójú ara rẹ̀
Nígbà tí olódodo ń lékè ariwo ayọ̀ ta;
Ẹni tí ó bo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ mọ́lẹ̀ kì yóò ṣe rere,
Ìbùkún ni fún ènìyàn náà tí ó bẹ̀rù Ọlọ́run nígbà gbogbo
Bí kìnnìún tí ń ké tàbí Beari tí ń halẹ̀
Ọmọ-aládé tí ó ṣe aláìmòye púpọ̀ ní ń ṣe ìwà ìkà púpọ̀ pẹ̀lú,
Ẹni tí ọkàn rẹ̀ kò balẹ̀ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ ìpànìyàn
Ẹni tí ń rìn déédéé ní yóò là,
Ẹni tí ó bá ro ilẹ̀ rẹ̀ yóò ní oúnjẹ lọ́pọ̀lọ́pọ̀
Olóòtítọ́ ènìyàn yóò rí ìbùkún gbà gan an
Ojúsàájú ṣíṣe kò dára,
Ahun ń sáré àti là
Ẹni tí ó bá ènìyàn kan wí yóò rí ojúrere ni nígbẹ̀yìn
Ẹni tí ó ja baba tàbí ìyá rẹ̀ lólè
Ọ̀kánjúwà ènìyàn a máa dá ìjà sílẹ̀,
Ẹni tí ó gbẹ́kẹ̀lé ara rẹ̀ jẹ́ aláìgbọ́n
Ẹni tí ó ń fi fún tálákà kì yóò ṣe aláìní ohunkóhun,
Nígbà tí ènìyàn búburú bá dórí ìjọba, àwọn ènìyàn a na pápá bora;