Wọ̀nyí ni àwọn òwe mìíràn tí Solomoni pa, tí àwọn ọkùnrin Hesekiah ọba Juda dà kọ.
KO
Copywork
Yoruba OYCB 잠언 25장
성경필사는 빠르게 끝내는 입력 훈련이 아니라, 한 절씩 말씀의 문장과 흐름을 다시 붙드는 시간입니다. 입력 내용은 이 브라우저에 임시 저장되며, 로그인하면 계정에도 저장됩니다.
소제목 단위로 진행 · 잠언
Ògo Ọlọ́run ní láti fi ọ̀rọ̀ kan pamọ́;
Bí ọ̀run ṣe ga tó tí ayé sì jì
Mú ìdàrọ́ kúrò lára fàdákà
Mú ènìyàn búburú kúrò níwájú ọba
Má ṣe gbé ara rẹ ga níwájú ọba,
ó sàn kí ó wí fún ọ pé, “Gòkè wá síyìn-ín,”
Ohun tí o ti fi ojú ara rẹ rí
Bí o bá ń ṣe àwíjàre rẹ níwájú aládùúgbò rẹ,
àìṣe bẹ́ẹ̀ ẹni tí ó gbọ́ ọ le dójútì ọ́
Ọ̀rọ̀ tí a sọ ní àkókò tí ó yẹ
Bí i yẹtí wúrà tàbí ohun ọ̀ṣọ́ ti wúrà dáradára
Bí títutù òjò yìnyín ní àsìkò ìkórè
Bí ojú ṣíṣú àti afẹ́fẹ́ láìsí òjò
Nípa sùúrù a lè yí ọba lọ́kàn padà
Bí ìwọ bá rí oyin, jẹ ẹ́ ní ìwọ̀nba
Má ṣe máa lọ sí ilé aládùúgbò rẹ nígbà gbogbo
Bí ọ̀pá, idà tàbí ọ̀kọ̀ tí ó mú
Bí eyín tí ó bàjẹ́ tàbí ẹsẹ̀ tí ó rọ
Bí ẹni tí ó bọ́ra kalẹ̀ ní ọjọ́ tí òtútù mú,
Bí ebi bá ń pa ọ̀tá rẹ, fún un ní oúnjẹ jẹ;
Nípa ṣíṣe báyìí, ìwọ yóò wa ẹ̀yín iná lé e lórí
Bí afẹ́fẹ́ gúúsù ti í mú òjò wá,
Ó sàn láti gbé ní ibi igun kan lórí òrùlé
Bí omi tútù sí ọkàn tí ń ṣe àárẹ̀
Bí ìsun tí ó di àbàtà tàbí kànga tí omi rẹ̀ bàjẹ́
Kò dára láti jẹ oyin àjẹjù,
Bí ìlú tí odi rẹ̀ ti wó lulẹ̀