Ẹlẹ́yà ni ọtí wáìnì, aláriwo sì ní ọtí líle;
KO
Copywork
Yoruba OYCB 잠언 20장
성경필사는 빠르게 끝내는 입력 훈련이 아니라, 한 절씩 말씀의 문장과 흐름을 다시 붙드는 시간입니다. 입력 내용은 이 브라우저에 임시 저장되며, 로그인하면 계정에도 저장됩니다.
소제목 단위로 진행 · 잠언
Ìbẹ̀rù ọba dàbí kíké e kìnnìún;
Iyì ni ó jẹ́ fún ènìyàn láti sá fún ìjà,
Ọ̀lẹ kì í ṣiṣẹ́ oko nígbà tí ó yẹ,
Ète ọkàn ènìyàn dàbí omi jíjìn;
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni wọ́n máa ń sọ pe àwọn ní ìfẹ́ àìṣẹ̀tàn,
Olódodo ènìyàn a máa gbé ìgbé ayé àìlábùkù
Nígbà tí ọba bá jókòó sórí ìtẹ́ rẹ̀ láti ṣe ìdájọ́
Ta ni ó le è wí pé, “Mo ti ṣe ọkàn mi ní mímọ́,
Ìwọ̀n èké àti òsùwọ̀n ìrẹ́jẹ
Kódà a mọ ọmọdé nípa iṣẹ́ rẹ̀
Etí tí ó ń gbọ́ àti ojú tí ó ń ríran
Má ṣe fẹ́ràn oorun, àìṣe bẹ́ẹ̀ ìwọ yóò di tálákà.
“Kò dára, kò dára!” ní ẹni tó ra ọjà máa ń wí;
Wúrà wà, iyùn sì wà rẹpẹtẹ,
Gba abọ́ ẹni tí ó ṣe onídùúró fún àlejò;
Oúnjẹ tí a fi ọ̀nà èrú rí máa ń dùn lẹ́nu ènìyàn,
Pa ètè rẹ mọ́ nípa wíwá ìmọ̀ràn
Olófòófó a máa tú àṣírí
Bí ènìyàn kan bá ṣépè fún baba tàbí ìyá rẹ̀,
Ogún tí a kójọ kíákíá ní ìbẹ̀rẹ̀
Má ṣe wí pé, “N ó sẹ̀san àṣìṣe rẹ yìí fún ọ.”
Olúwa kórìíra òdínwọ̀n èké.
Olúwa ni ó ń ṣe olùdarí ìgbésẹ̀ ènìyàn.
Ìdẹ̀kùn ni fún ènìyàn láti ṣe ìlérí kíákíá
Ọlọ́gbọ́n ọba tú ènìyàn búburú ká;
Àtùpà Olúwa ń ṣe àwárí ẹ̀mí ènìyàn
Ìfẹ́ àti òdodo pa ọba mọ́,
Ògo àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin ni agbára wọn,
Ìgbájú ìgbámú àti ìfarapa máa ń mú ibi lọ,