Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan Damasku:
JA
Copywork
Yoruba OYCB Isaiah 17장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Isaiah
Àwọn ìlú Aroeri ni a ó kọ̀sílẹ̀
Ìlú olódi ni yóò pòórá kúrò ní Efraimu,
“Ní ọjọ́ náà ni ògo Jakọbu yóò sá;
Yóò sì dàbí ìgbà tí olùkórè kó àwọn
Síbẹ̀síbẹ̀ irúgbìn díẹ̀ yóò ṣẹ́kù,
Ní ọjọ́ náà, àwọn ènìyàn yóò gbójú sókè sí Ẹlẹ́dàá wọn,
Wọn kò ní wo àwọn pẹpẹ mọ́,
Ní ọjọ́ náà àwọn ìlú alágbára rẹ̀, yóò dàbí ẹ̀ka ìkọ̀sílẹ̀, àti ẹ̀ka téńté òkè tí wọ́n fi sílẹ̀ nítorí àwọn ọmọ Israẹli. Gbogbo wọn yóò sì di ahoro.
Nítorí ìwọ ti gbàgbé Ọlọ́run ìgbàlà rẹ;
Nítorí náà, bí ẹ tilẹ̀ mú àṣàyàn igi tí ẹ sì gbin àjàrà tí ó ti òkèrè wá,
Kíyèsi i, ìrunú àwọn orílẹ̀-èdè—
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn ènìyàn ń bú
Ní aginjù, ìpayà òjijì!