“Ṣùgbọ́n gbọ́ nísinsin yìí, ìwọ Jakọbu ìránṣẹ́ mi,
JA
Copywork
Yoruba OYCB Isaiah 44장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Isaiah
Ohun tí Olúwa wí nìyìí
Nítorí èmi yóò da omi sí ilẹ̀ tí ń pòǹgbẹ
Wọn yóò dàgbàsókè gẹ́gẹ́ bí i koríko nínú pápá oko tútù,
Ọ̀kan yóò wí pé, ‘Èmi jẹ́ ti Olúwa’;
“Ohun tí Olúwa wí nìyìí
Ta ni ó dàbí ì mi? Jẹ́ kí o kéde rẹ̀.
Má ṣe wárìrì, má ṣe bẹ̀rù.
Gbogbo àwọn tí ń gbẹ́ ère jásí asán,
Ta ni ó mọ òrìṣà kan tí ó sì ya ère,
Òun àti nǹkan rẹ̀ wọ̀nyí ni a ó dójútì;
Alágbẹ̀dẹ mú ohun èlò,
Gbẹ́nàgbẹ́nà fi ìwọ̀n wọ́n ọ́n
Ó gé igi kedari lulẹ̀,
Ohun èlò ìdáná ni fún ènìyàn;
Ìlàjì igi náà ni ó jó nínú iná;
Nínú èyí tí ó kù ni ó ti ṣe òrìṣà, ère rẹ̀;
Wọn kò mọ nǹkan kan, nǹkan kan kò yé wọn;
Kò sí ẹni tí ó dúró láti ronú,
Ó ń jẹ eérú, ọkàn ẹlẹ́tàn ni ó ṣì í lọ́nà;
“Rántí àwọn nǹkan wọ̀nyí, ìwọ Jakọbu,
Èmi ti gbá gbogbo ìkùnà rẹ dànù bí i kurukuru,
Kọrin fáyọ̀, ẹ̀yin ọ̀run, nítorí Olúwa ló ti ṣe èyí;
“Ohun tí Olúwa wí nìyìí
ta ni ó ba àmì àwọn wòlíì èké jẹ́
ẹni tí ó gbé ọ̀rọ̀ àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ jáde
ta ni ó sọ fún omi jíjìn pé, ‘Ìwọ gbẹ,
ta ni ó sọ nípa Kirusi pé, ‘Òun ni Olùṣọ́-àgùntàn mi