Èyí ni ohun tí Isaiah ọmọ Amosi rí nípa Juda àti Jerusalẹmu.
JA
Copywork
Yoruba OYCB Isaiah 2장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Isaiah
Ní ìgbẹ̀yìn ọjọ́
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni yóò wá, wọn yóò sì wí pé,
Òun ó ṣe ìdájọ́ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè,
Wá, ẹ̀yìn ará ilé e Jakọbu,
Ìwọ ti kọ àwọn ènìyàn rẹ sílẹ̀,
Ilẹ̀ wọn kún fún fàdákà àti wúrà,
Ilẹ̀ ẹ wọn kún fún ère,
Nítorí náà ni a ó ṣe rẹ ènìyàn sílẹ̀
Wọ inú àpáta lọ,
Ojú agbéraga ènìyàn ni a ó rẹ̀ sílẹ̀
Olúwa àwọn ọmọ-ogun ní ọjọ́ kan ní ìpamọ́
nítorí gbogbo igi kedari Lebanoni, tó ga tó rìpó
nítorí gbogbo òkè gíga ńlá ńlá
fún ilé ìṣọ́ gíga gíga
fún gbogbo ọkọ̀ àwọn oníṣòwò
Ìgbéraga ènìyàn ni a ó tẹ̀ lórí ba
gbogbo ère òrìṣà yóò pòórá.
Àwọn ènìyàn yóò sálọ sínú ihò àpáta
Ní ọjọ́ náà ni àwọn ènìyàn yóò máa sọ
Wọn yóò sálọ sínú ihò ìsàlẹ̀ àpáta
Dẹ́kun à ń gba ènìyàn gbọ́,