Nítorí Sioni èmi kì yóò dákẹ́,
Àwọn orílẹ̀-èdè yóò rí òdodo rẹ,
Ìwọ yóò sì jẹ́ adé dídán ní ọwọ́ Olúwa,
Wọn kì yóò pè ọ́ ní ìkọ̀sílẹ̀ mọ́
Gẹ́gẹ́ bí ọ̀dọ́mọkùnrin tí í gbé ọ̀dọ́mọbìnrin níyàwó,
Èmi ti fi olùṣọ́ ránṣẹ́ sórí odi rẹ ìwọ Jerusalẹmu;
àti kí ẹ má ṣe fún òun pẹ̀lú ní ìsinmi
Olúwa ti búra pẹ̀lú ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀
ṣùgbọ́n àwọn tí ó bá kóórè rẹ̀ ni yóò jẹ ẹ́,
Ẹ kọjá, ẹ kọjá ní ẹnu ibodè náà!
Olúwa ti ṣe ìkéde
A ó sì pè wọ́n ní Ènìyàn Mímọ́,