Ta nì eléyìí tí ó Edomu wá,
JA
Copywork
Yoruba OYCB Isaiah 63장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Isaiah
Èéṣe tí aṣọ yín fi pupa
“Èmi nìkan ti dá tẹ ìfúntí wáìnì;
Nítorí ọjọ́ ẹ̀san wà ní ọkàn mi
Mo wò, ṣùgbọ́n kò sí ẹnìkan láti ṣe ìrànwọ́.
Mo tẹ orílẹ̀-èdè mọ́lẹ̀ nínú ìbínú mi;
Èmi yóò sọ nípa àánú Olúwa,
Ó wí pé, “Lóòtítọ́ ènìyàn mi ni wọ́n,
Nínú gbogbo ìpọ́njú wọn, inú òun pẹ̀lú bàjẹ́
Síbẹ̀síbẹ̀ wọ́n ṣọ̀tẹ̀
Lẹ́yìn náà ni àwọn ènìyàn rẹ̀ rántí ọjọ́ ìgbà n nì,
ta ni ó rán apá ògo ti agbára rẹ̀
ta ni ó síwájú wọn la àwọn ọ̀gbun nì já?
gẹ́gẹ́ bí ọ̀wọ́ ẹran tí ó lọ sí pápá oko,
Bojú wolẹ̀ láti ọ̀run kí o sì rí i
Ṣùgbọ́n ìwọ ni baba wa,
Èéṣe Olúwa tí o fi jẹ́ kí a ṣáko kúrò ní ojú ọ̀nà rẹ
Fún ìgbà díẹ̀ ni àwọn ènìyàn rẹ fi gba ibi mímọ́ rẹ,
Àwa jẹ́ tìrẹ láti ìgbà n nì;