Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan Babeli èyí tí Isaiah ọmọ Amosi rí.
JA
Copywork
Yoruba OYCB Isaiah 13장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Isaiah
Gbé àsíá sókè ní orí òkè gbẹrẹfu,
Mo ti pàṣẹ fún àwọn ẹni mímọ́ mi,
Gbọ́ ohùn kan ní àwọn orí òkè,
Wọ́n wá láti ọ̀nà jíjìn réré,
Ẹ hu, nítorí ọjọ́ Olúwa súnmọ́ tòsí,
Nítorí èyí, gbogbo ọwọ́ ni yóò rọ,
Ẹ̀rù yóò gbá wọn mú,
Kíyèsi i, ọjọ́ Olúwa ń bọ̀
Àwọn ìràwọ̀ ojú ọ̀run àti ìkójọpọ̀ wọn
Èmi yóò jẹ ayé ní ìyà nítorí ibi rẹ̀,
Èmi yóò jẹ́ kí ọkùnrin kí ó wọn
Nítorí náà èmi yóò jẹ́ kí àwọn ọ̀run kí ó wárìrì;
Gẹ́gẹ́ bí egbin tí à ń dọdẹ rẹ̀,
Ẹnikẹ́ni tí a bá gbámú ni a ó wọ́ nílẹ̀ tuurutu,
Àwọn ọ̀dọ́mọdé wọn ni a ó fọ́ sí wẹ́wẹ́ níṣojú wọn,
Kíyèsi i, èmi yóò ru àwọn Media sókè sí wọn,
Ọrùn wọn yóò ré àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin lulẹ̀;
Babeli, ohun ọ̀ṣọ́ àwọn ìjọba
A kì yóò tẹ̀ ibẹ̀ dó mọ́
Ṣùgbọ́n àwọn ẹranko igbó ni yóò dùbúlẹ̀ níbẹ̀,
Ìkookò yóò máa gbó ní ibùba wọn,