Ègbé ni fún ọ, Arieli, Arieli,
JA
Copywork
Yoruba OYCB Isaiah 29장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Isaiah
Síbẹ̀síbẹ̀ èmi yóò dó ti Arieli
Èmi yóò sì wà ní bùba yí ọ ká níbi gbogbo,
Ní ìrẹ̀sílẹ̀, ìwọ ó sì máa sọ̀rọ̀ láti ilẹ̀ wá;
Ṣùgbọ́n àwọn ọ̀tá rẹ, yóò dàbí yanrìn kíkúnná,
Olúwa àwọn ọmọ-ogun yóò wá
Lẹ́yìn náà,
àti bí ìgbà tí ẹni tí ebi ń pa ń lá àlá pé òun ń jẹun,
Ẹ bẹ̀rù kí ẹnu kí ó yà yín,
Olúwa ti mú oorun ìjìká wá sórí i yín:
Fún un yín gbogbo ìran yìí kò yàtọ̀ sí àwọn ọ̀rọ̀ tí a fi èdìdì dì sínú ìwé kíká. Bí ẹ bá sì fún ẹni tí ó lè ka ìwé kíká náà, tí ẹ sì sọ fún un pé, “Jọ̀wọ́ ka èyí,” òun yóò dáhùn pé, “Èmi kò lè kà á; a ti dì í ní èdìdì.”
Tàbí bí ẹ bá fún ẹni tí kò lè ka ìwé kíká náà tí ẹ sì sọ pé, “Jọ̀wọ́ ka èyí,” òun yóò dáhùn pé, “Èmi kò mọ̀ ọ́n kà.”
Olúwa wí pé:
Nítorí náà lẹ́ẹ̀kan sí i èmi yóò ya
Ègbé ni fún àwọn tí ó lọ sí ọ̀gbun
Ẹ̀yin dojú nǹkan délẹ̀,
Ní àìpẹ́ jọjọ, ǹjẹ́
Ní ọjọ́ náà adití yóò gbọ́ ọ̀rọ̀ ìwé kíká náà,
Lẹ́ẹ̀kan sí i àwọn onírẹ̀lẹ̀ yóò yọ̀ nínú Olúwa:
Aláìláàánú yóò pòórá,
àwọn tí wọ́n fi ọ̀rọ̀ kan mú ẹnìkan di ẹlẹ́bi,
Nítorí náà, èyí ni ohun tí Olúwa, ẹni tí ó ra Abrahamu padà sọ sí ilé Jakọbu:
Nígbà tí wọ́n bá rí i láàrín àwọn ọmọ wọn,
Gbogbo àwọn tí ń rìn ségesège ní yóò jèrè ìmọ̀;