“Dìde, tànmọ́lẹ̀, nítorí ìmọ́lẹ̀ rẹ ti dé,
JA
Copywork
Yoruba OYCB Isaiah 60장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Isaiah
Kíyèsi i, òkùnkùn bo ilẹ̀ ayé
Àwọn orílẹ̀-èdè yóò wá sí ìmọ́lẹ̀ rẹ,
“Gbé ojú rẹ sókè, kí o sì wò.
Nígbà náà ni ìwọ yóò wò tí ojú rẹ yóò máa dán,
Ọ̀wọ́ ìbákasẹ yóò bo gbogbo ilẹ̀ rẹ,
Gbogbo agbo ẹran ìlú Kedari ni a ó kójọ sọ́dọ̀ rẹ,
“Ta ni àwọn wọ̀nyí tí ń fò lọ bí i kurukuru,
Lóòtítọ́ àwọn erékùṣù bojú wò mí;
“Àwọn àjèjì yóò tún ògiri rẹ mọ
Gbogbo ẹnu-bodè rẹ ni yóò wà ní ṣíṣí sílẹ̀,
Nítorí pé orílẹ̀-èdè tàbí ilẹ̀ ọba tí kì yóò sìn ọ́ ni yóò parun;
“Ògo Lebanoni yóò wá sí ọ̀dọ̀ rẹ,
Àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin àwọn apọ́nilójú rẹ yóò
“Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a ti kórìíra rẹ, a sì kọ̀ ọ́ sílẹ̀,
Ìwọ yóò mu wàrà gbogbo orílẹ̀-èdè
Dípò idẹ, èmi ó mú wúrà wá fún ọ,
A kì yóò gbọ́ nípa rògbòdìyàn ní ilẹ̀ rẹ mọ́,
Òòrùn kì yóò sì jẹ́ ìmọ́lẹ̀ rẹ ní ọ̀sán mọ́,
Òòrùn rẹ kì yóò sì wọ̀ mọ́,
Lẹ́yìn náà ni gbogbo àwọn ènìyàn rẹ yóò di òdodo
Èyí tí ó kéré jù nínú yín yóò di ẹgbẹ̀rún (1,000) kan,