Wò ó, ọba kan yóò jẹ nínú òdodo
JA
Copywork
Yoruba OYCB Isaiah 32장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Isaiah
Ẹnìkọ̀ọ̀kan yóò jẹ́ bí ibi ìṣápamọ́ kúrò lọ́wọ́ afẹ́fẹ́
Nígbà náà ni ojú àwọn tí ó rí kò ní padé mọ́,
Ọkàn àwọn oníwàdùwàdù ni yóò là tí yóò sì yè,
A kò ní pe òmùgọ̀ ní ọlọ́lá mọ́
Nítorí òmùgọ̀ sọ̀rọ̀ òmùgọ̀,
Ibi ni gbogbo ọgbọ́n àwọn ìkà ènìyàn jẹ́,
Ṣùgbọ́n ọlọ́lá ènìyàn a máa pète ohun ńlá
Ẹ̀yin obìnrin tí ẹ ti gba ìtẹ́lọ́rùn gidi
Ní ó lé díẹ̀ ní ọdún kan
Wárìrì, ẹ̀yin obìnrin onítẹ̀lọ́rùn;
Ẹ lu ọmú yín fún pápá ìgbádùn náà,
àti fún ilẹ̀ àwọn ènìyàn mi,
Ilé olódi ni a ó kọ̀sílẹ̀,
títí a ó fi tú Ẹ̀mí sí wa lórí láti òkè wá,
Ẹ̀tọ́ yóò máa gbé ní inú aṣálẹ̀
Èso òdodo náà yóò sì jẹ́ àlàáfíà;
Àwọn ènìyàn mi yóò máa gbé ní ibùgbé àlàáfíà,
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé yìnyín ti tẹ́jú igbó pẹrẹsẹ
báwo ni ẹ ó ti jẹ́ alábùkún tó,