Síbẹ̀síbẹ̀, kò ní sí ìpòrúru kankan mọ́ fún àwọn tí ó wà nínú ìbànújẹ́. Nígbà kan rí ó rẹ ilẹ̀ Sebuluni sílẹ̀ àti ilẹ̀ Naftali pẹ̀lú, ṣùgbọ́n ní ọjọ́ iwájú, yóò bu ọ̀wọ̀ fún Galili ti àwọn aláìkọlà, ní ọ̀nà Òkun, ní ẹ̀gbẹ̀ẹ̀gbẹ́ Jordani.
JA
Copywork
Yoruba OYCB Isaiah 9장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Isaiah
Àwọn ènìyàn tí ń rìn nínú òkùnkùn
Ìwọ ti sọ orílẹ̀-èdè di ńlá;
Nítorí gẹ́gẹ́ bí ọjọ́ tí a ṣẹ́gun Midiani,
Gbogbo bàtà jagunjagun tí a ti lò lójú ogun
Nítorí a bí ọmọ kan fún wa,
Ní ti gbígbòòrò Ìjọba rẹ̀ àti àlàáfíà rẹ̀ ni kì yóò ní ìpẹ̀kun.
Olúwa ti dojú iṣẹ́ kan kọ Jakọbu;
Gbogbo ènìyàn ni yóò sì mọ̀ ọ́n—
Àwọn bíríkì ti wó lulẹ̀
Ṣùgbọ́n Olúwa fún àwọn ọ̀tá Resini ní agbára láti dojúkọ wọ́n
Àwọn ará Aramu láti ìlà-oòrùn àti Filistini láti ìwọ̀-oòrùn.
Ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn náà kò tí ì yípadà
Nítorí náà ni Olúwa yóò ṣe ké àti orí àti ìrù
àwọn àgbàgbà, àti àwọn gbajúmọ̀ ní orí,
Àwọn tí ó ń tọ́ àwọn ènìyàn wọ̀nyí ṣì wọ́n lọ́nà,
Nítorí náà, Olúwa kì yóò dunnú sí àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin
Nítòótọ́ ìwà búburú ń jóni bí iná,
Nípasẹ̀ ìbínú Olúwa àwọn ọmọ-ogun
Ní apá ọ̀tún wọn yóò jẹrun,
Manase yóò máa jẹ Efraimu, nígbà tí Efraimu yóò jẹ Manase