Ègbé ni fún adé ìgbéraga,
JA
Copywork
Yoruba OYCB Isaiah 28장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Isaiah
Kíyèsi i, Olúwa ní ẹnìkan tí ó le, tí ó sì lágbára,
Adé ìgbéraga àwọn ọ̀mùtí Efraimu,
Òdòdó tí ó ń rọ náà tí í ṣe ẹwà ògo rẹ̀,
Ní ọjọ́ náà Olúwa àwọn ọmọ-ogun
Òun yóò sì jẹ́ ẹ̀mí ìdájọ́ òdodo
Àwọn wọ̀nyí pẹ̀lú ta gbọ̀nọ́ngbọ̀nọ́n fún ọtí wáìnì
Gbogbo orí tábìlì ni ó kún fún èébì
“Ta ni ẹni náà tí ó ń gbìyànjú àti kọ́?
Nítorí tí í ṣe: báyìí ni orí,
Ó dára báyìí, pẹ̀lú ètè àjèjì àti ahọ́n àìmọ̀
àwọn tí ó sọ fún wí pé,
Fún ìdí èyí, ọ̀rọ̀ Olúwa sí wọn yóò di pé,
Nítorí náà, ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa, ẹ̀yin ẹlẹ́gàn,
Ẹ fọ́n pé, “Àwa ti bá ikú mulẹ̀,
Nítorí náà, báyìí ni Olúwa Olódùmarè wí:
Èmi yóò fi ìdájọ́ ṣe okùn òsùwọ̀n
Májẹ̀mú yín tí ẹ bá ikú dá ni a ó fa igi lé;
Nígbàkígbà tí ó bá ti wá ni
Ibùsùn kúrú púpọ̀ fún ìnara lé lórí,
Olúwa yóò dìde sókè gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe
Ní ìsinsin yìí ẹ dákẹ́ ẹlẹ́yà ṣíṣe,
Tẹ́tí kí o sì gbọ́ ohùn mi,
Nígbà tí àgbẹ̀ kan bá tu ilẹ̀ láti gbìn
Nígbà tí òun bá ti tẹ́ ojú ilẹ̀ rẹ̀ pẹrẹsẹ
Ọlọ́run rẹ̀ tọ́ ọ ṣọ́nà
Nítorí a kò fi ohun èlò ìpakà dili,
A gbọdọ̀ lọ ìyẹ̀fun kí a tó ṣe àkàrà;
Gbogbo èyí pẹ̀lú ti ọ̀dọ̀ Olúwa àwọn ọmọ-ogun wá,