Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan aginjù lẹ́bàá Òkun.
JA
Copywork
Yoruba OYCB Isaiah 21장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Isaiah
Ìran tí a ń fojú ṣọ́nà fún ni a ti fihàn mí
Pẹ̀lú èyí, ìrora mu mi lára gírígírí,
Ọkàn mí dàrú,
Wọ́n tẹ́ tábìlì,
Èyí ni ohun tí Olúwa sọ fún mi:
Nígbà tí ó bá rí àwọn kẹ̀kẹ́ ogun
Òun sì kígbe pé, kìnnìún kan,
Wò ó, ọkùnrin kan ni ó ń bọ̀ wá yìí nínú kẹ̀kẹ́ ogun
Ẹ̀yin ènìyàn mi, tí a gún mọ́lẹ̀ ní ilẹ̀ ìpakà,
Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan Dumahi.
Alóre náà dáhùn wí pé,
Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan Arabia.
gbé omi wá fún àwọn tí òǹgbẹ ń gbẹ;
Wọ́n sá kúrò lọ́wọ́ idà,
Èyí ni ohun tí Olúwa sọ fún mi: “Láàrín ọdún kan, gẹ́gẹ́ bí ìwọ̀fà tí ó wà lábẹ́ ọgbà, í ti í kà á, gbogbo ògo ìlú Kedari yóò wá sí òpin.
Àwọn tafàtafà tí ó sálà, àwọn jagunjagun ìlú Kedari kò ní tó nǹkan.” Olúwa, Ọlọ́run Israẹli ni ó ti sọ̀rọ̀.